Home / Aworan (page 5)

Aworan

Eyin Eyan mi Tani eyin ma di IBO yin fun ninu a won mejeji.

Eyin Eyan mi Tani eyin ma di IBO yin fun ninu a won mejeji. Jonathan tabi buhari

Read More »

E je kawa imo ku imo Ewo lo to na ninu awon oro won yi

1) Ki lori lobe to fi wa iru so wo  2) ki lori lobe to fi waru owo  3) ki lori to fi garu owo  4) ki lori lobe to fi wa owo ru 5) ki lori lobe to fi ...

Read More »

Kinni eyin npe ladugbo yin

Wonwo re lede wa legbado kinni eyin npe ladugbo yin ,obe re ninu ata dindin

Read More »

Gbolohun kan fun

E dakun e ba mi wi Gbolohun kan fun

Read More »

Ọ̀RỌ̀ ÌSÍTÍ

Húùm…ètò ìsèlú tiwa-ntiwa kò yẹkí ó mú ìjà wá bí ó bá se wípé l’òtítọ́ la n’ìfẹ́ ará ìlú l’ọ́kàn, k’ára ó leè dẹ t’ẹrú-t’ọmọ yàtọ̀ sí ìsèlú bí-o-ba-o-pá, bí-o-kò-báa-kó- bu- bùú-l’ẹ́sẹ̀, èyí tó wọ́pọ̀ l’órílẹ̀ èdè wa!!. Àwa ọmọ ...

Read More »

Ejowo gbolohun kan fun igbeyawo yii

E ko gbolohun kan fun igbeyawo yii

Read More »

‎ITUMỌ Olowo

  Alaye: Ọpọlọpọ eniyan ro pe gbogbo awọn ti o wa ni ipo nlanla bii: gomina, aarẹ, alaga kansu,…tabi awọn to n gun ọkọ nlanla tabi to n gbe’le nlanla nikan ni ‪#‎olowo‬ laimọ wipe ko ri bẹ rara. ‪#‎ITUMỌ‬: Itumọ olowo ...

Read More »

Latest Yoruba movie 2014- Emi gangan

No retreat no surrender as barrister Morenikeji rather die than chicken from this case that stands as an examination to his professional competence and gateway to success… A blockbuster you can’t afford to miss. Featuring: Odunlade Adekola, Dupe Jaiyesimi, Dele ...

Read More »

Ejo oruko kan fun egun yi

Read More »

Ere Ọpọlọ

O ṣọ #50 nu, ẹni to ri owo na wa ra nkan #10 ni ilé itaja rẹ o si fun ni #40.  ‪#‎Ibeere‬: elo ni iye ti o padanu lapapọ?

Read More »