Mo ki gbogbo wa pata lokunrin ati lobinrin, lomode ati lagba wipe a ku ise oni, a si ku abo sori eto wa eto yin, eto Idile Alayo ti ose yi. E wa nkan fidile tabi ki e gbiyanju fidile ...
Read More »Eeto Owe L’esin Oro
YAKUB BUKKY – Nje a tun ti de loni gegebi ise wa ni gbogbo ojoru. Oro enikokan wa koni dojuru oo (amin), a ki gbogbo kaabo si akootun eeto yin, eeto wa owe l’esin oro, oro l’esin owe, ti oro ...
Read More »Iwure Owuro Toni 04-05-2016
E MAA WI TELE MI : ……… *Owo ko ni ri mi sa. *Oju owo ko ni pon mi. *Ojo ibukun mi ko ni di ojo abuku. *Alaaanu mi ko ni ko’yin si mi. *Edumare ma je ki n teni ...
Read More »Iwure Osu Tuntun 01-05-2016
E MAA WI TELE MI : ……… *Osu karun-un yii, osu ire owo ni fun mi. *Osu ire ile kiko ni fun mi. *Osu ti maa ra oko ayokele. *Osu igbega lenu ise mi ni. *Osu idunnu ni yoo je ...
Read More »Ibeere Toni
Egbo eyin o ogbon,…nje oda ki Iyawo ile o mo ko orun fun okore ? ….tabi ki oko naa o ko fun Iyawo re?……. Iru nkan wonyi se o ma ndin Ife Ku ni abi oma tubo mufe gbile si???????????
Read More »Oko mi ati iya re loba aye mi je
Akole oke yi lo se apejuwe oro arabinrin kan , eyi to fi esun kan iya oko re wipe o gba arisiki oun fun omo (oko re) Nigbati obinrin yi so oro , emi bi leere wipe SE OKO SAA ...
Read More »Iwure Owuro Ipari Osu
E MAA WI TELE MI : ….. *Airije-airimu nile aye mi ti dopin. *Ibanuje ninu aye mi ti dopin. *Ijakule ninu aye mi ti dopin. *Ise mi ko ni dojuru *Ogun aye ko ni borii mi. *Oju owo ko ni ...
Read More »Fi ere si temi Eledumare
Ojulu! ojo nan re bi anan sugbon o ti pe odun kan bayi Eledua modupe, ibi ti ore nan de duro maje ko taku sibe o, fi ere si temi Eledumare, MAJE KIN KAABAMO BO TI WU KORI, orewa toripe ...
Read More »Orewa Abi Iwonan Ti Gbagbe Ile !
Orewa abi iwonan ti gbagbe ile, toripe eniyan to so ile nu ti so apo ‘ya ko, ajo ko dabi ile lo d’ifa fun agiliti to pada wa tun ile-baba re se, se ki se pe o ti gbagbe orirun ...
Read More »Oba Erediauwa Ti Waja
Ojulu ooooo! iku ti pa abiri abiri ti rorun alakeji oooo! iku ti pa okan lara awon omo ODUDUWA Oba-Benin, gbogbo eyin ojulowo omoYORUBAatata e ku araferaku eni re OBA-EREDIAUWA ti ile-benin. bo ba de orun ko se orun re. ...
Read More »