Bi a se n mura lati wo inu odun tuntun lo, ni aisun odun taa wayii, ile itura alaja metalelogota (63) kan an jona lo lowolowo bayii ni ilu Dubai eleyii ti won ko ti kapa ina naa. Bi a ...
Read More »Oserebirin wo leyii, Se e damo bi??
E wo ohun ti enikan so nipa ile epo Bovas to wa niluu Ibadan
Awon arije ni madaru, ika, odaju, ole, wobia, wonbiliki le po ni Naijiria loooto, sugbon awon eniyan rere ko ti tan lawujo wa. Okan ninu won ni alase ile epo Bovas to kale silu Ibadan. Bakan naa ni awon eniyan ...
Read More »Ijamba oko niluu Eko lojo odun keresimesi
Ti e ba muti, e ma wako; ti e ba wako, e ma muti. Okunrin kan lo koja lo sorun lojo odun keresimesi to koja yii ni akoko ti gbogbo eniyan n yo ayo iwasaye Jesu olugbala araye. Ijamba oko ...
Read More »Owo ti te Jaguda, Mohammed Isah to lu komisanna olopaa meji ni jibiti
Sebi ojo gbogbo ni tole, ojo kan pere ni tolohun. Owo awon olopaa ilu Eko ti te omo gambari onijibiti kan ti oruko re n je Mohammed Isah, to lu komisanna ipinle Ondo ati Anambra ni jibiti. Omokunrin onijibiti naa ...
Read More »Ikini odun lati owo Olayemi Olatilewa Oniroyin Agbaye
Olayemi, odun to n bo yii, odun emi ati iwo ni. Eyin e fota sile ki won ma gbogun. E fika eniyan sile ki won ma soogun. Mo tile tun gbo wi pe awon kan tun lo n bogun onire. ...
Read More »Yinka Ayefele sodun fun awon alaini ati omowewe
Aimoye awon omo wewe ni won pejo si bi ayeye odun keresimesi ati babakeresi ti ile ise redio Fesh FM ti Yinka Ayefele eleyii to waye ni Music House, ile orin Ayefele, to kale siluu Ibadan. Asekagba naa lo waye ...
Read More »“Oju Mimiko ni PDP yoo fi poora nipinle Ondo” – Oloye egbe APC
Okan pataki ninu awon oloye egbe APC nipinle Ondo, Niran Sule-Akinsuyi, ti so yanya wi pe niseju Gomina Olusegun Mimiko ni egbe oselu PDP ipinle naa yoo fi di ohun a-fi-seyin teegun fiso. Oro yii lo n so nigba to ...
Read More »Faleke n mura ija nipinle Kogi *Omo oloogbe Abubakar Audu n be leyin re.
*Omo oloogbe Abubakar Audu n be leyin re. *Kilode ti Tinubu ko da soro naa? Lati Ọwọ Olayemi Olatilewa Lojo Aje to koja yii ni rugudu ti n lo lagbo oselu nipinle Kogi tun bureke si i nigba ti Ogbeni ...
Read More »Esun idigunjale la o fi kan eni to ba gbegidina ti n gbowo odun” Olopaa Ipinle Ogun
Komisanna awon olopaa ipinle Ogun, Ogbeni Abdulmajid Ali ti kede wi pe,ile ise olopaa ipinle Ogun ti wa ni imurasile lati gbogun ti iwa idaran to seese ko suyo lasiko poposinsin odun taa wa yii. Ninu oro Ogbeni Abdulmajid, eleyii ...
Read More »