Home / Iroyin Pajawiri (page 119)

Iroyin Pajawiri

Ofin mokanla to le mu awo ara dabi omo tuntun jojolo

Orisun 1 E yee sa ara yin sinu oorun koja bo ti ye lo. Paapa julo, e sora fun awon oorun lati bi ago mewaa aaro si ago meji osan. Orisii oorun yii a maa mu ki awo eniyan o ...

Read More »

“Iyawo mi n yale, o tun bimo ale fun mi”: Alabi yari ni kootu Ikorodu

Orisun   Ogbeni Alabi Rasheed, eni odun mejidinlaadota (48) ti gbe iyawo re, Sherifat, lo si ile ejo lati tu yigi igbeyawo odun mewaa to wa laaarin won ka lOjobo ose to koja yii. Gege bi alaye Alabi ni Ikorodu ...

Read More »

Baalu Aare Buhar ti bale niluu Iran

Aare Muhammadu Buhari ti bale ni Tehran to wa ni orileede Iran nibi ti yoo ti maa joko se ipade eleeketa iru e ti egbe awon orileede ti n gbe epo robi jade fun awon orileede agbaye.

Read More »

Saraki gba Basketmouth lalejo niluu Abuja

Aare ile igbimo asofin agba, Bukola Saraki, gba Basketmouth lalejo ninu ile re to wa niluu Abuja

Read More »

“Ijoba APC gbodo je ki eto eko ofe rinle de ileewe giga” – Atiku

Igbakeji Aare ile Naijiria nigba kan ri, Alaaji Atiku Abubakar ti ro ijoba to wa lode yii, eleyii to wa lowo egbe oselu APC, lati je ki eto eko ofe ti won se ileri re kari gbogbo eka ikekoo patapata, ...

Read More »

Simisola Omoayan: Omidan ti n filu dara

O ti wa daju wi pe kosi oun ti okunrin se ti obirin o le se. Bi eniyan ba si foju kere ata, afaimo ki iru eni bee ma kabamo leyin oro. Eni Edua Oke ba fe ni i fun ...

Read More »

“Eyan Mayweather” ni awo orin tuntun Olamide Ogbeni (Mr) . Baddo

Olamide, Ogbeni (Mr) Baddo ti kede ojo ti yo ju awo orin re tuntun sigboro aye. Awo orin tuntun to pe akole re ni “Eyan Mayweather” ni yoo maa dagboro ru, bere lati ojo ketalelogun osu kokanla odun yii (23/11/15). ...

Read More »

Mercy Aigbe alaso oge pade Toke Makinwa

Awon Yoruba bo, won ni tode-tode ni i se alaso tuntun. Joojumo ni Mercy n sodun, Mercy Aigbe alaso oge.  Mercy tun pade Toke, sorosoro ori redio ati telifisan ti oun naa feran oge lagbo ariya.

Read More »

Maheeda di Pasito oloro itunnu

Kosi eni ti Olorun ko le fi owo to lokan. Maheeda, okan ninu awon olorin ile Naijiria, ti ma n bora sile nihoho tele ti wa di eni ti n gba awon eniyan niyanju bayii pelu oro itunnu ti n ...

Read More »

Ika eniyan wo lo yo oju Ibrahim sa lo?

Okunrin olokada kan ti won pe oruko re ni Ibrahim ni won sadeede ba oku re loju titi laaaro yii ni agbegbe Alaba Suru to wa loju ona masose Badagry niluu Eko. Igba ti won yoo ye okunrin naa wo, ...

Read More »