Olayemi Olatilewa Alaga egbe oselu APC eka ti ipinle Ondo, ogbeni Isaac Kekemeke ti fesun kan Gomina Olusegun Mimiko to je omo egbe oselu PDP nipa wi pe owo bi tirilionu kan naira (N1 trillion) ni gomina ti je mole ...
Read More »Ile ise Ologun seleri owo tabua fun eni to ba ri Boko Haram
Olayemi Olatilewa Ile ise Ologun ile Naijiria ti se afihan foto awon ogbologbo alakatakiti esin Islam, Boko Haram bi ogorun (100) eleyii ti won on wa lati mu. Awon wonyii ni won se apejuwe won gege oloye agba ti ...
Read More »Foto Mercy Aigbe meje (7) to ta lenu bi ataare
Ti ija ba wa ni be, e je a pari kia. Awon Yoruba si bo won ni tomo eni ba daa kawi, kii se ka fi saya. Egan ni he, Mercy Aigbe ta lenu bee lodun yungbayungba. Olayemi ti mo ...
Read More »Erin jade lenu Ajimobi leyin to feyin Ladoja janle nile ejo
Erin ayo lenu gomina Abiola Ajimobi nigba ti won pe e lori ago wi pe o ti feyin Adewolu Ladoja janle nile ejo. Gomina Abiola Ajimobi ni ile ejo ti n risi awuyewuye eto idibo gomina ti da lare eleyii ...
Read More »Ooni tuntun wo ilu Ile-Ife tilu-tifon
Omooba Adeyeye Enitan Ogunwusi ti wo ilu Ile-Ife fun imurasile fun iwuye re ti o waye ni kopekope yii
Read More »E wa wo ise opolo to fakiki
Ise awon asaraloge ni ki won tunrase. Sugbon nigba mi-in, won tun le baraje. Sebi bise ba se gba ni won se n se e. Ise opolo ni ise tiata, awon onitiata ni won se ise opolo. Foto: eni ti ...
Read More »Asiri Tony Blair ati George Bush tu: Blair ti lo toro aforojin ni ti e
Olootu ile Biritiko nigba kan ri, Tony Blair, ti toro aforojin lowo gbogbo aye pelu bose lediapopo mo ijoba ile Amerika eleyii ti George Bush se adari fun lati fogun ja ile Iraq. Alaye yii ni Ogbeni Tony se lori ...
Read More »Foto: Davido se baba gidi fomo re
Sebi tori omo naa la se n sise… Omoomo baba olowo
Read More »Mama o fe e gba: Iyabo Ojo ati omo re
Edumare ma pa omo folomo. Ti eniyan ba ri omo Iyabo Ojo, eniyan le sebi boya aburo re ni. Iya gan-an ni ko si fe gba yii. Oga ju!
Read More »Photos: Meet the New Ooni Of Ife, Oba Adeyeye Enitan Ogunwusi (Kabiyesi O)
ki Ade ko pe lori ki Bata pe lese o,Kabiyesi o.. Adeyeye Enitan Ogunwusi from the Geisi ruling house has been unveiled as the new Ooni of Ife. Moshood Adeoti, secretary to the Osun state government, confirmed this in an ...
Read More »