Ọ̀nà Jìbìtì 2Awon miiran maa n duro si opopona bi eni ti moto won baje. Won le mu omo ileewe kan tabi meji si egbe won gege bi eni to nilo iranlowo. Awon to ba duro ti won ti ko ...
Read More »Buhari bá ìpínlè̩ Eko ké̩dùn
Buhari bá ìpínlè̩ Eko ké̩dùn – Ìròyìn lati o̩wó̩ Yínká Àlàbí Ojo buruku esu gbomi mu ni ojo isinmi oni je fun awon ara agbegbe Amuwo Odofin ni adugbo FESTAC.Ijamba ina naa bere ni aago mesan-an aaro. Opa epo ni ...
Read More »Nítorí Àrùn Coronavirus Ìjọba Àpapọ̀ Ní Káwọn Arìnrìnàjò Láti Orílẹ̀èdè Amẹ́ríkà, Gẹ̀ẹ́sì, Faransé Àtorilẹ̀èdè Mọ́kànlá Míràn O Gbélé Wọn
Bákan náà ni Ìjọba àpapọ̀ tún ṣàlàyé pé àṣẹ yìí ló bẹ̀rẹ̀ sí ní fi ẹsẹ̀ múlẹ̀, bẹ̀rẹ̀ láti ọjọ́ Sátidé, ọjọ́ kọkànlélọ́gún oṣù kẹta ọdún 2020.
Read More »Ikú agbábó̩ò̩lù: LMC fa ìbínú yo̩
Ikú agbábó̩ò̩lù: LMC fa ìbínú yo̩– Iroyin lati Owo Akinwale Taophic. Latari iku odo agbaboolu, Chineme Martin’s, eni ti o pade iku ojiji ni abala akoko ifigagbaga ose ketalelogun liigi orileede wa Nigeria, NPFL, ti o waye laarin Nasarawa United ...
Read More »Ilé ẹjọ́ kòtẹ́milọ́rùn wọ́gilé ìyọnípò Oshiomole gẹ́gẹ́ bíi alága ẹgbẹ́ òṣèlú APC
Ilé ẹjọ́ kòtẹ́milọ́rùn wọ́gilé ìyọnípò Oshiomole gẹ́gẹ́ bíi alága ẹgbẹ́ òṣèlú APC
Read More »Alárùn kòkòrò corona e̩lé̩è̩ké̩ta fara hàn
Arabinrin ti o sese ti ilu London de ni o bere si nii wuko ti o si n se kata. Ni eyi ti o mu ki o fara re sile fun ayewo coronavirus.
Read More »Ọ̀nà Jìbìtì
Bi ara ipede Radio Naigeria O.Y.O ni aye atijo, won ni, “Ifunra loogun agba, pasa ko funra, o ja sina, aja ko funra, aja jin, ti onile naa ko ba funra, ole ni yoo ko lo”. Eyi ni o difa fun gbogbo awa ti a maa n gbe moto lo si ibi inawo.
Read More »Àríwá Nàìjíríà, Ẹ Sọ Ẹran Jọ̀bọ̀jọ̀bọ̀ Nù Bí Ẹ Ṣe Yọ Sanusi – Soyinka
Ọ̀jọ̀gbọ́n Wọlé Soyinka ti bu ẹnu àtẹ́ lu bí Ìjọba ìpínlẹ̀ Kano, lábẹ́ ìsàkóso Gómìnà Abdullahi Umar Ganduje, lórí bó ṣe rọ Lamido Sanusi lóyè, gẹ́gẹ́ bí Emir ìlú Kano.
Read More »Osinbajo wọ́gilé ìrìn-àjò rẹ̀ lẹ́yìn tí ọ̀kan lára ẹ̀ṣọ́ rẹ̀ kú lọ́nà pápákọ̀ òfurufú
Osinbajo wọ́gilé ìrìn-àjò rẹ̀ lẹ́yìn tí ọ̀kan lára ẹ̀ṣọ́ rẹ̀ kú lọ́nà pápákọ̀ òfurufú Ọ̀kan lára àwọn ẹ̀ṣọ́ ìgbákejì Ààrẹ, Ọ̀jọ̀gbọ́n Yemi Osinbajo sàgbákò ikú ójijì nínú ìjàmbá alùpùpù lọ́jọ́ Ẹtì. Ali Gómìnà, tó jẹ́ ọlọ́pàá rìpẹ́tọ̀ gbẹ́mì ín mì ...
Read More »Fayemi, ilẹ̀ Oòduà (Yorùbá) kìí ṣe Kano tí wọn ti ń yọ Emir lórí oyè… Alaafin
Àwọn ọmọ Nàìjíríà lórí ojú òpó ìkànsíraẹni Twitter ti dásí ọ̀rọ̀ láàrin Gómìnà Ìpínlẹ̀ Ekiti, Kayode Fayemi àti àwọn ọba ní ìpínlẹ̀ náà. Èyí kò sẹ́yìn lẹ́tà tó jáde lórí ẹ̀rọ ayélujára níbi tí Aláàfin Ọ̀yọ́, Ọba Lamidi Olayiwola Adeyemi ...
Read More »