Ààre ilé-ìgbìmò asòfin Bukola Saraki pàdé Akòwé ìjoba gbogbogbò tuntun (SGF)Boss Mustapha.
Read More »Ambode wo okò ojú omi láti rin ìrìn àjò lórí omi .
Dr. Akinwumi Ambode, Gómìnà ìpínlè Èkó se ayeye láti we okò ojú omi tí ó sèsè rà, okò ojú omi náà sì wà fún ìpínlè Èkó, bí ó se so wípé àwon n sisé láti jé kí ìrìnàjò orí omi ...
Read More »Àwon akékòó ilé-èkó gíga Calabar is ayeye ìkékojáde won ní àrà òtò .
Àwon akékojáde ti ilé-ìwé giga Calabar (UNICAR) se ayeye ìkékojáde won ní àrà òtò. ” kò rorùn béè ni kò lera …ayò ni a ka gbogbo rè sí!!!”òkan nínú won ni ò pín èyí sí orí èro ayélujára (Facebook).
Read More »Olópàá kan ní orílè èdè Ghana fi pàsán na arábìnrin yí ní ìdí nítorí ó kò láti w’onú èwòn .
Olópàá tí ó n sojú àgó olópàá Domping ní orílè èdè Ghana, Ase Emmanuel Osei ni won ti fi èsùn kàn látàrí wípé ó fi pàsán na arábìnrin odún mókàndílógbòn (29) tí a mò sí Sarah Darko ní ...
Read More »Gbajúgbajà òsèré, Mercy Aigbe pín ìròyìn ìbànújé.
Òsèré, ìyá, àti oní káràkátà ti pín aí orí èro ayélujára láti polongo wípé bàbá òun ti dágbére f’áyé.
Read More »Jamil Balogun, omo Tiwa Savage yo pèlú àrà òtò nínú àwòrán tí ó yà.
Omokùnrin Tiwa Savage, Tunji ‘Tee Billz Balogun ti è ti rewà jù. Gbajúgbajà olórin Tiwa Savage pín àwòrán omo rè tí ó rewà, Jamil Balogun nàà yo ní àrà òtò nínú aso aláwò pupa tí ó yí orùn ká.
Read More »Buhari ti búra fún Boss Mustapha gégé bíi akòwé ìjoba gbogboogbò (SGF).
Àare Muhammadu Buhari ti se ìbúra fún akòwé ìjoba gbogboogbò tuntun tí ó n jé Boss Mustapha . Ayeye ìbúra náà wáyé ní yàrá ìgbìmò Ààre.
Read More »Olópàá tí owó tè nígbà tí ó n gba owó èyin ní ojà Yola.
Gégé bí ò n lò èro ayélujára tí ó gbé ní Yola tí ó pín ìròyìn ìsèlè yí se so, olópàá tí àwòrán rè hàn ní ìsàlè yí ní won yà nígbà tí ó n GBA owó èyin ...
Read More »Terry G se ayeye ojó ìbí fún omokùnrin rè, Teerex nígbà tí ó pé odún márùn-ún.
Omokùnrin Terry G, Teerex pé omo odún Márùn-ún bàbá rè sì se ayeye ojó ìbí náà fun pèlú àwon òrò tí ó dùn tí ó pín sí orí èro ayélujára (Instagram).
Read More »Cossy Orjiakor ní ilé-ìwòsàn tí ó fé se isé abe kí ìdí rè le yo.
Cossy Orjiakor tí a mò wípé óní àyà ni a ti gbó tí ó ti kérora nípa ìdí rè tí ó kéré lénu ojó meta yí, sùbón báyìí ó ti lo sí ilé-ìwòsàn láti sisé abe kí ìdí ...
Read More »