Home / Iroyin Pajawiri (page 88)

Iroyin Pajawiri

Odu Ifa Iwure Toni Ki Bayi Wipe…

Ekaaro eyin eniyan mi, aojiire bi? Aku ise ana o, oni a sanwa sire gbogbo o ase. Odu ifa iwure toni ki bayi wipe: Òkan fìkìkìkì babalawo oladeji difa fun oladeji eyiti won nfojojumo njuwe re fun iku, won ni ...

Read More »

Kabiyesi Sango O!!!

Read More »

Yoruba Bo Won Ni Agbomojo Lomo N Moju…

Mo ki gbogbo Omo Yoruba Atata pata nile-loko ati leyin odi wipe a ku dede asiko yi, mo si ki awa ololufe eto Idile Alayo wipe e ku abo sori eto wa, eto yin, eto Ido Alayo ti ose yi. ...

Read More »

Idile Alayo Toni – 17.09.2016 (E Gbo Bi Atejise Na Ti Lo)

Mo ki gbogbo Omo Yoruba Atata pata nile-loko ati leyin odi wi pe a ku aseku odun emi wa yoo se pupo re laye, layo ati ni alafia ara. Mo si ki awa ololufe eto yi, wi pe e ku ...

Read More »

Iyawo re o, a mo eni towu oooo!

Owo idana o po ooo 5,000 pere ni oooooo

Read More »

N je e ran’ti iwe yii?

Read More »

Ijinle Ninu Oro Ifa Fi Ye Wa Nipa Bi Ila Se De Atelewo Wa.

Ekaaro eyin eniyan mi, aojiire bi? Ojó oni a san wa o ao ri tiwa se o ase. Gegebi awon opolopo eniyan se maa nsoro wipe “atewolabala ao meni to ko” lotito la ba ila latelewo wa sugbon imo ijinle ...

Read More »

Ifa Iwure Toni Jade Ninu Odu Ifa Ogundigara

Ekaaro eyin eniyan mi, aojiire bi? Aku aseku odun o emin wa yio se pupo re laye awon alaseku yio bawa se o, ako ni rogun inira o ase. Ifa iwure toni jade ninu odu ifa Ogundigara Ifa naa ki ...

Read More »

Olojo Ibi Toni – Arabinrin Adetona Banke

Mo layo lati so fun yin wipe oni ni ojo ibi Arabinrin Adetona Banke ti won je okan gboogi ninu ebi Omo Yoruba Atata. Olojo ibi oni a ki yin e ku ayo oni, e o se pupo re laye ...

Read More »

Ogulutu Oro Toni – 11.09.2016

Hummmmmm erora gbogbo yan ale yan ale Nje O mo wipe ohunti ntan lodun eegungun bi? Woo Orewa Kosi nkan towa nta ju ohun towa nile lo bi Iwo naa ba toju titie dada yio rewa yio wuyi loju Gbomi ...

Read More »