Home / Idile

Idile

sibeki

Àjọ EFCC ti ń wá àwọn tó wà nídìí ṣogúndogójì CBEX

Èyí ni àwòrán mẹ́rin nínú àwọn tó wà nídìí ṣogúndogójì CBEX. Àjọ EFCC ti ń wá wọn

Read More »
kabiyesi

Èyí wuyì àbí kò wuyì?

Ẹ jẹ́ kí á ṣe Kábíyèsí fún Aláàfin Ọ̀wọ́adé, kí Èdùmàrè ó fi ìgbà wọn tu ìlú lára

Read More »

Orun Ire Ooooo

ERIN WOOOOOOO. Iku da Oro iku shei’ika, Iku mu eni rere lo.

Read More »

Igbeyawo omo Adewale Ayuba fakiki

Idunnu obi ni ki omo o yan ko si yanju. Omo taa to, to si duro gbeko ni i pada di omo gidi lowo awon obi re. Eyi  ni a le pe ni itan Tiwalade Ayuba lowo baba re. Ayo ...

Read More »

E ba wa dasi oro yii

Nje ohun to dara wa ninu ki awon okunrin maa na awon iyawo ile won? Kini obirin le se to le mu okunrin siwo soke na won?

Read More »