Home / Demo Blog With Mappage 2

Demo Blog With Map

Ọlọ́pàá ò lè dáwa lọ́wọ́kọ́ àti sèwọ́de àyájọ́ EndSARS, -Oduala

Ọlọ́pàá ò lè dáwa lọ́wọ́kọ́ àti sèwọ́de àyájọ́ EndSARS, -Oduala Ọrẹ Òtítọ́jù Ọ̀kan nínú àwọn tó ṣagbátẹrù ìwọ́de ta ko àwọn ọlọ́pàá SARS t’íjọba ti fòfin dè, Bọlatito Oduala, tí ìnagijẹ rẹ̀ ń jẹ́ Savvy Rinu ti sọ pé kò ...

Read More »
atorumu

Orí kó mi yọ lọ́wọ́ àwọn agbébọn – Gómìnà Samuel Ortom

Orí kó mi yọ lọ́wọ́ àwọn agbébọn – Gómìnà Samuel Ortom Fẹ́mi Akínṣọlá Gómìnà ìpínlẹ̀ Benue Samuel OPrtom ti fìdí ọ̀rọ̀ múlẹ̀ pé lóòótọ́ làwọn agbébọn ṣe ìkọlù sí òun lógúnjọ́ oṣù Kẹta. Gómìnà náà sọ pé àwọn agbébọn tí ...

Read More »
Olubadan

Awon omo Alade yari: Yoruba fe gba’ra re lowo ajeji Fulani to n tele basubasu

Akeredolu yari kanle. Olubadan ni ki Seriki Sasa fi owo sibi owo o gbe… . Akeredolu yari kanle. Olubadan ni ki Seriki Sasa fi owo sibi owo o gbe. Gani Adams n yona lenu lori laasigbo Wakili. Sunday Igboho si ...

Read More »
ifa

Kùtùkùtù Ìrèní Laó He Erè Nígbódù Oòni

Òní laó roko létí opónÒla laó sákà lágbèrùKùtùkùtù ìrèní laó he erè nígbódù oòniKáyáa múlé pontíKámú òdèdè rokàKáfi agbada dínranÀwèje wèmu nípón omodé wòyí lójúÒrìsà lópabuké tánLódákún sábaro nídìíOmo-ojo húnsáré gíríjo-gíríjoOmo-ojo húnsáré gìrìjo-gìrìjoIlé-ifón kògba obàtáláÈlàgboro kògba òrìsàOjúgboro ni tàfínÈlàgboro ni ...

Read More »

Òyèkú bìwòrì

Òyèkú bìwòrì,Gbóró,gbóró,gìdì ? òyèkú b’ìwòrì?Ajan gbóró gìdìAdífáfún lájosìnOmo ab’oya ríreÈyí tio bo òrìsà obìnrin làÈròpo àti tòfàB’ifá bá..bíni níbèOya ni ko maa bo ~Translation ~ Òyèkú bìwòrìGbóró gbóró gìdìAjan gbóró gìdìCast ifá for lájosìnThe one that worship oya with blessingsThe ...

Read More »

Àwọn ilé mi, ọkọ̀ 12, ọmọ àti ènìyàn méje pẹ̀lú ₦500m ni mo sọnù ní Igangan – Seriki Fulani

Àwọn ilé mi, ọkọ̀ 12, ọmọ àti ènìyàn méje pẹ̀lú ₦500m ni mo sọnù ní Igangan – Seriki Fulani Fẹ́mi AkínṣọláSeriki Fulani ní ìlú Igangan níjọba ìbílẹ̀ Ibarapa nípìnlẹ̀ Oyo, Alhaji Salihu Abdulkadir ti fẹ̀sù kan pé ajafẹ́tọ ọmọ Yorùbá, ...

Read More »

À ń fún àwọn èèyàn lọ́rùn pa ni-Monsuru Afurasí

À ń fún àwọn èèyàn lọ́rùn pa ni-Monsuru Afurasí Fẹ́mi Akínṣọlá Àtubọ̀tán ayé ń kànkùn gbọ̀ngbọ̀n.Àwọn àgbà bọ̀, wọ́n ní bí a bá ń rin ìrìnàjò, kí á wo ẹni tí à ń bá lọ, nítorí àti ilé àti òde ...

Read More »
endsars

Ilẹ̀ Gẹ̀ẹ́ṣì fèsì lórí ìwọ́de EndSARS

Ilẹ̀ Gẹ̀ẹ́ṣì fèsì lórí ìwọ́de EndSARS Fẹ́mi Akínṣọlá Ìjọba orílẹ̀-èdè United Kingdom, ti fèsì lórí ìwé ẹ̀sùn tí àwọn ọmọ Nàìjíríà fọwọ́ sí, tí wọ́n sì fi ránṣẹ́ síi. Ìwé náà ló ń ké sí àwọn orílẹ̀-èdè àgbáyé tó wà ...

Read More »
Amotekun

Ìpínlẹ̀ Ọ̀yọ́ kéde orúkọ àwọn aláàbò Àmọ̀tẹ́kùn rẹ̀

Ìpínlẹ̀ Ọ̀yọ́ kéde orúkọ àwọn aláàbò Àmọ̀tẹ́kùn rẹ̀ Fẹ́mi Akínṣọlá Olójú kò nì-ín lajúẹ̀ sílẹ̀, kí tàlùbọ̀ ó yí wọ̀ọ́. Bẹ́ẹ̀ ni bí èèyàn bá joyè Arẹ̀kú, ó yẹ kó lè pitú lábẹ́ agọ̀. Èyí ló mú kí àwọn ìjọba ...

Read More »
sanwoolu

Gómìnà Eko, Sanwó-Olú jẹ́jẹ̀ẹ́ ìrànwọ́ fún àwọn ọlọ́pàá tó lùgbàdi

Gómìnà Eko, Sanwó-Olú jẹ́jẹ̀ẹ́ ìrànwọ́ fún àwọn ọlọ́pàá tó lùgbàdi Fẹ́mi Akínṣọlá Ṣé wọ́n ní ìgbẹ̀yìn làásìgbò kan kìí bímọ tó rọ̀. Làásìgbò tó wáyé ní ìpínlẹ̀ Èkó láìpẹ́ yìí ti mú kí Gómìnà ìpińlẹ̀ náà, Babájídé Sanwó-Olú ó pàsẹ ...

Read More »