Yínká ÀlàbíYoruba bo̩, wo̩n ni “aisan lo se e wo, a ko ri ti o̩lo̩jo̩ se”. Ko ki n se iroyin mo̩ pe iku ti poju gbajugbaja osere ori itage de ni o̩jo̩ aje o̩se̩ yii. Agba osere yii fi ...
Read More »
Yínká ÀlàbíYoruba bo̩, wo̩n ni “aisan lo se e wo, a ko ri ti o̩lo̩jo̩ se”. Ko ki n se iroyin mo̩ pe iku ti poju gbajugbaja osere ori itage de ni o̩jo̩ aje o̩se̩ yii. Agba osere yii fi ...
Read More »Arápájà di Igbákejì Alága ẹgbẹ́ PDP níhà Gúúsù Orílẹ̀ yìí Ọrẹ Akínṣọlá Ṣé bóṣe wu Ọlọ́run Ọba ní-ín sọlá, èèyàn tó bá wù Ú ní-Ìn ṣe lógo.Igbákejì gómìnà ìpínlẹ̀ Ọ̀yọ́ nígbààa kan, Ọ̀gbẹ́ni Taofeek Arapaja, ti jáwé olúbori sípò Ìgbákejì ...
Read More »A dúpẹ́ púpọ̀ lọ́wọ́ Baálẹ̀ Yemọja, Ìyá Omítọ̀nàdé, Ẹbí, Ará, gbogbo Àgbà àti Ọmọdé… Ìbà Olódùmarè, ọdún pé, ọdún jọ. .To all friends, fans and well wishers, we’re grateful.
Read More »Ọlọ́pàá ò lè dáwa lọ́wọ́kọ́ àti sèwọ́de àyájọ́ EndSARS, -Oduala Ọrẹ Òtítọ́jù Ọ̀kan nínú àwọn tó ṣagbátẹrù ìwọ́de ta ko àwọn ọlọ́pàá SARS t’íjọba ti fòfin dè, Bọlatito Oduala, tí ìnagijẹ rẹ̀ ń jẹ́ Savvy Rinu ti sọ pé kò ...
Read More »Orí kó mi yọ lọ́wọ́ àwọn agbébọn – Gómìnà Samuel Ortom Fẹ́mi Akínṣọlá Gómìnà ìpínlẹ̀ Benue Samuel OPrtom ti fìdí ọ̀rọ̀ múlẹ̀ pé lóòótọ́ làwọn agbébọn ṣe ìkọlù sí òun lógúnjọ́ oṣù Kẹta. Gómìnà náà sọ pé àwọn agbébọn tí ...
Read More »Akeredolu yari kanle. Olubadan ni ki Seriki Sasa fi owo sibi owo o gbe… . Akeredolu yari kanle. Olubadan ni ki Seriki Sasa fi owo sibi owo o gbe. Gani Adams n yona lenu lori laasigbo Wakili. Sunday Igboho si ...
Read More »Òní laó roko létí opónÒla laó sákà lágbèrùKùtùkùtù ìrèní laó he erè nígbódù oòniKáyáa múlé pontíKámú òdèdè rokàKáfi agbada dínranÀwèje wèmu nípón omodé wòyí lójúÒrìsà lópabuké tánLódákún sábaro nídìíOmo-ojo húnsáré gíríjo-gíríjoOmo-ojo húnsáré gìrìjo-gìrìjoIlé-ifón kògba obàtáláÈlàgboro kògba òrìsàOjúgboro ni tàfínÈlàgboro ni ...
Read More »Òyèkú bìwòrì,Gbóró,gbóró,gìdì ? òyèkú b’ìwòrì?Ajan gbóró gìdìAdífáfún lájosìnOmo ab’oya ríreÈyí tio bo òrìsà obìnrin làÈròpo àti tòfàB’ifá bá..bíni níbèOya ni ko maa bo ~Translation ~ Òyèkú bìwòrìGbóró gbóró gìdìAjan gbóró gìdìCast ifá for lájosìnThe one that worship oya with blessingsThe ...
Read More »Àwọn ilé mi, ọkọ̀ 12, ọmọ àti ènìyàn méje pẹ̀lú ₦500m ni mo sọnù ní Igangan – Seriki Fulani Fẹ́mi AkínṣọláSeriki Fulani ní ìlú Igangan níjọba ìbílẹ̀ Ibarapa nípìnlẹ̀ Oyo, Alhaji Salihu Abdulkadir ti fẹ̀sù kan pé ajafẹ́tọ ọmọ Yorùbá, ...
Read More »À ń fún àwọn èèyàn lọ́rùn pa ni-Monsuru Afurasí Fẹ́mi Akínṣọlá Àtubọ̀tán ayé ń kànkùn gbọ̀ngbọ̀n.Àwọn àgbà bọ̀, wọ́n ní bí a bá ń rin ìrìnàjò, kí á wo ẹni tí à ń bá lọ, nítorí àti ilé àti òde ...
Read More »