Ka ji ni kutukutuKa mu ohun ipin ko’pind’Ifa fun Olomo-ajiba’re-padeEmi ni mo ji ni kutukutu ti mo f’ohun ipin ko’pinEmi ni mo ba ire pade nigba gbogbo ori mi apeereAteteniranAtetegbeni ju OrishaKo si Orisha ti danni gbe leyin ori eniOri ...
Read More »Demo Blog With Map
Ẹyọ De Ọlọ́bẹ̀ Oko
Ọ̀̀rọ̀ mi gbogbo ka sàì yọ́ ikin nínú gẹ̀ẹ̀rẹ̀gẹ̀ Mo sé ní ìwúre ní ojúmọ́ tòní wípé gbogbo ẹ̀sẹ̀ tí a sẹ̀ Ọlọ́run, osó,ajẹ́ àbí ènìyàn bi tiwa ni, tó ń fa ìdíwọ́ kan àbí ìkejì, mo súre fún wa ...
Read More »Odu Ifa,”Irosun Oyeku” Cast Today For Ose Ifa
Looking at Odu Ifa, “Irosun Oyeku” cast today for Ose Ifa, I can advise all Priests and Priestesses to imbibe calmness in their characters so that they can always achieve their desires. Secondly, the stanza contains one of the Yoruba ...
Read More »Ifá naa ki bayi wípé…
Ifá gba gbogbo akápò re niyanju wípé ki won o rubo nitori ki a baa le ri orí ayé wa, ki a baa le de ile ileri, ifá ni nkan yio soro tabi le die fun awon ti won ba ...
Read More »Kọ́kọ́rọ́ ayọ̀ mi: Máfi le ènìyàn lọ́wọ́ !
Máfi le ènìyàn lọ́wọ́ Ènìyàn ò daWọ́n lè sọ́ sómi Mo sé ní ìwúre ní ọ̀sẹ̀ titun tòní wípé kọ́kọ́rọ́ ayọ̀ èmi àti ẹ̀yin, Ọlọ́run ọba kò ní fí le ọ̀tá lọ́wọ́ o. Kọ́kọ́rọ́ Ayọ̀ wa kò ní bọ́ só mi. ...
Read More »Ifá naa ki bayi wípé..
Ekaaro eyin eniyan mi, aojiire bi? Aku ise ana o Eledumare ninu aanu re yio fi ire gbogbo wa wari loni o Àse.Ifá yi gbawa niyanju wipe ki a bo ifá pelu obi meji ati agbebo adiye, ki a si ...
Read More »Ní Ojúmọ́ Ọjọ́ Àbámẹ́ta Tòní – #Kojoda #Yoruba #Orisa
Òsùn gbó ríró, kí o má dubúlẹ̀Òòró gangan laa bósùnÒsùn dé o Alàwòrò Ọlọ́run ọba ma jẹ kí gbogbo wa saarẹ Mo sé ní ìwúre fun orí kọ̀ọ̀kan wa ní ojúmọ́ ọjọ́ Àbámẹ́ta tòní wípé àìsàn kéré tóbi aráyé kò ní ...
Read More »Tàgiiri
Tàgiiri ma yí nìsó Ara rẹ lokùn Ara rẹ ní ajé gbe ńso
Read More »Ẹ̀yẹ̀lé
Yiyẹ̀ lonyẹ́ ẹ̀yẹ̀lé, Ayé ayẹ̀ wá kàlẹ̀, Rirọ lonrọ àdábà lọrún, Ayé yio rọrún fún wá jẹ̀,
Read More »Ifá naa ki bayi wipe: Osa Alawure (Osa Otura) – Otua Meji
Ekaaro eyin eniyan mi, aojiire bi? Aku isinmi ana o, adura wa yio gba, ori buruku koni je tiwa loni o Àse. Mo nfi akoko yi nki gbogbo onisese patapata kaakiri agbaye wipe aku aseyori odun ifá agbaye o , a ku odun a sin ku iyedun o, emin wa yio se pupo re ninu ola ati idera lase Eledumare.
Read More »