Èàkàn ẹgbẹ́ òṣèlú APC mií Lanre Rasak dágbére fáyé Èèkàn ẹgbẹ́ òṣèlú APC nípìńlẹ̀ Èkó, Lanre Razak ti jáde láyé lẹ́ni ọdún mẹ́rìnléláàdọ́rin. Kí ikú ó pajú èèyàn dé lójijì ti wá fẹ́ ẹ̀ kúrò ní ń tí wọ́n kíìyàn ...
Read More »Demo Blog With Map
Covid-19- kó̩ ló pa Babatunde Oke
Covid-19 ko lo pa Babatunde OkeOwuro oni ni won kede iku Alaga ijoba ibile Onigbongbo, Ogbeni Babatunde Oke. Gbogbo iroyin to gbee ni ajakale arun coronavirus lo paa. Won ni baba naa se aisan ranpe ni nnkan bii ose meta ...
Read More »Sáká lára dá,Bàbá Ọbásanjọ́ kò l’árùn Kofi-19
Sáká lára dá,Bàbá Ọbásanjọ́ kò l’árùn Kofi-19 Fẹ́mi Akínṣọlá Agbẹnusọ fún Bàbá Ọbásanjọ́, Kehinde Akinyemi ló fi léde bẹ́ẹ̀ nínú àtẹjáde ní Ọjọ́ Ìsinmi pé àyẹ̀wò fihàn pé kò ní àrùn Kòrónáfairọ̀ọ̀sì. Akinyemi ní Ọjọ́ Keje, Oṣù Kẹjọ, ọdún 2020 ...
Read More »Gbọ́ ń táwọn èèkàn ìlú ṣọ lẹ́yìn Búrùjí Kashamu
Gbọ́ ń táwọn èèkàn ìlú ṣọ lẹ́yìn Búrùjí Kashamu Bí ọmọ èèyàn bá wá sílé ayé, ìgbàgbọ́ Yorùbá ní pérúfẹ́ ẹni bẹ́ẹ̀ wáyé wá nájà ni. Ènìyàn ò sáà lè tajà tán kò sùn sínú ọjà, àti pé n tí ...
Read More »A ti gba 800 bílíọ̀nù owóòlú tí wọ́n jí kó, àwọn 1,400 ti dèrò ẹ̀wọ̀n– Lai Mohammed
A ti gba 800 bílíọ̀nù owóòlú tí wọ́n jí kó, àwọn 1,400 ti dèrò ẹ̀wọ̀n– Lai Mohammed Ẹdìyẹ ń làágùn, ìyẹ́ ni kò jẹ́ kó hàn.Ìjọba àpapọ̀ ti sọ pé òun ti gba owó tó lé ní ẹgbẹ̀rin bílíọ̀nù náírà ...
Read More »Fayemi kó àjàkálè̩ àrùn covid-19
Fayemi kó àjàkálè̩ àrùn covid-19 Gomina kayode Fayemi ti ipinle Ekiti to darapo pelu awon gomina to ko ajakale arun coronavirus.Fayemi kede eyi lori ero Twitter re pe saka ni ara oun da sugbon ayewo fihan pe arun naa wa ...
Read More »Video: Egungun festival
Ifá ní yini yini kí eni le se òmíràn
Adífáfún ifátérú tí se omokùnrin ìgódó,Èdùmàrè àwa yìn ó kí o tún le se òmírán.?????I give thanks to Elédùmarè, for everything he has done for me, orí modupe, Ifa modupe, Egbe aye ati t’òrun modupe lowo yin.?????? Thanks to everyone ...
Read More »APC kò ní ì ṣe ìdìbò ní ìpínlẹ̀ Òǹdó àyàfi.. Olùdíje kan
APC kò ní ì ṣe ìdìbò ní ìpínlẹ̀ Òǹdó àyàfi.. Olùdíje kan Láìpẹ́ yìí ni ìròyìn kàn pé ìgbìmọ̀ ẹgbẹ́ òṣèlú All Progressive Congress (APC) tó ń ṣe àyẹ̀wò àwọn olùdíje lábẹ́ ẹgbẹ́ náà sọ pé Segun Abraham ni kò ...
Read More »Dino Melaye tún fàwo orin míràn ló̩lè̩
Dino Melaye tún fàwo orin míràn ló̩lè̩ Yorùbá bò̩, wó̩n ní ‘àrà ò kì ń tán nínú alárà nígbà kankan’. Gbajugbaja Semeyo Dino Melaye tí gbogbo ènìyàn mò̩ bí e̩ní mo̩ owó tún gbé àwo orin jáde nípa olórí àjo̩ ...
Read More »