D’banj pín èróngbà rè nípa ìdàméwàá. E jè rí, àwon omo Nàíjíríà ti da l’óhùn bí ó ti yé.
Read More »Cristiano Ronaldo àti Georgina Rodriguez kí omobìnrin káàbò, Alana Martina .
Cristiano Ronaldo ti kí omo rè kerin káàbò, Alana Martina ni orúko rè. E kú oríre Ooo.
Read More »Ó ye kí ó se ìgbéyàwó ní ojó kejì osù kejìlá odún yí (2nd of December) sùgbón ó ti di olóògbé.
Gégé bí ò n lò èro ayélujára (Facebook)se so, odókùnrin yí ye kí ó se ìgbéyàwó ni osù kejìlá sùgbón ó ti di olóògbé. Ó kú nínú ìjàmbá pèlú àwon tí ó kùn rè. Kí olórun te sí aféfé rere. ...
Read More »Wizkid ni ó gbé igbá orókè gégé bi okùnrin àkókó ní bi àmì èye AFRIMA ti odún yí ó sì pa Davido láyò.
Wizkid pa Davido, Techno àti àwon míràn tí ó wá fún àmì èye AFRIMA ti odún yí láyò. Wizkid gba èbùn fún orin rè ” Come closer ” tí ó ko pèlú Drake.
Read More »Jackie Appiah dàbí egbin nínú aso ìbílè tí ó wò.
Òsèré orílè èdè Ghana, Jackie Appiah, èyí rewà ju kí èèyàn fi ojú paáré lo, òsèré yí ló pin sí orí èro ayélujára láti pín àwòrán tí ó rewà yí níbi tíó ti wo aso ìbílè tí a mò ...
Read More »Ebube Nwagbo fi enu ko eja nlá tí ó n jé Dolphin ní Dubai fún ìsinmi.
Òsèré Ebube Nwagbo tí ó wà ní ìsinmi lówólówó ní Dubai ti pin sí orí èro ayélujára (Instagram) àwòrán aso ìwè rè pèlú bí ó se n wè l’ódò àti eja nlá tí ó n jé Dolphin .
Read More »Ìmúra Nana Akua Addo fún AFRIMA ti odún yí.
Òsèré orílè èdè Ghana , Nana Akua Addo ya ni lénu pèlú ìmúra rè lo sí AFRIMA odún yí.
Read More »Tiwa Savage gbégbà orókè níbi àmì èye AFRIMA 2017 tí ó sì gba èye náà mó Yemi Alade lówó .
Òdóbìnrin olórin àkókó ní ikò Marvins , Tiwa Savage gbé igbá orókè ní ibi àmì èye AFRIMA ti odún yí gégé obìnrin àkókó ní ikò adúláwò ti odún yí. Tiwa Savage pa Yemi Alade, Aramide àti Seyi Shey ...
Read More »Isé abe tí ó bùáyà, Hushpuppi káàbámò lábé abe , ó sì gba àwon èèyàn n’ímòràn.
Léyìn isé abe ; Hushpuppi káàbámò, ó sì gba àwon èèyàn n’ímòràn.
Read More »Ejò sèbé tí mo won pa ní Ofoni Sagbama ní ìpínlè Bayelsa .
Sèbé nlá ni won pa ní agbègbè Ofoni ní ìjoba ìbílè Sagbama ní ìpínlè Bayelsa . E wo bí won se ge fún obè aláta yéríyérí.
Read More »