Home / Tag Archives: Aalo apamo

Tag Archives: Aalo apamo

Aalo apamo Toni: Itan aja ati ijapa!

Alo ooooooo, alo oooooooo. Itan aja ati ijapa. Ni ojo kan iyan mu ni ilu kan, ko si onuje, baba agbe kan wa, to je ipe ohun ni kan ni o gbin n kan si oko re. Ti awon ara ...

Read More »

Aalo apamo – Mayaki Ojo

Aalo apamo Obi awe kan aje de oyo, baba kukuru de fila bentigo, kini nboba jeun ti kii mu sibi dani? Aguntan baba mi kan lailai, aguntan baba mi kan lailai, owoo ni nje kii je agbado. ( Ahon, oko, ...

Read More »