Ẹ ẹ̀ ṣi nọ́ńbà mú l’Ọyọ, gbogbo owó yín tí mo bá ná, ẹ ó rí n tí mo fi se…..Seyi Makinde Fẹ́mi Akínṣọlá Àwọn àgbà ní bí Ọlọ́run bá sẹ̀rí ì rẹ,jẹ́ kí èèyàn náà ó sẹ̀rí ì rẹ ...
Read More »Ọmọọba mẹwàá ló du òyè pẹ̀lú mi – Aláàfin Ò̩yó̩
Ọmọọba mẹwàá ló du òyè pẹ̀lú Adeyẹmi, tó sì já mọ lọ́wọ́. Fẹ́mi Akínṣọlá Ọlayiwọla Adeyẹmi Kẹta, ti pé ẹni ọdún mọ́kànlélọ́gọ́rín lókè eèpẹ̀ bẹ́ẹ́ ló ti lo ọdún méjìdínláàdọ́ta lórí ìtẹ́ àwọn baba ńlá rẹ̀. Òjò ti ń pa ...
Read More »llé iṣẹ́ ọ̀lọ́pàá ,ẹ dá ìgbaniwọlé tí ẹ gùnlé dúró… Àṣẹ ilé ẹjọ́
llé iṣẹ́ ọ̀lọ́pàá ,ẹ dá ìgbaniwọlé tí ẹ gùnlé dúró… Àṣẹ ilé ẹjọ́ Fẹ́mi Akínṣọlá Ṣé àwọn àgbà ní ilé tí a fi itọ́ mọ, ìrì ni yóò wo. Ọbẹ̀ tí a fi èké pilẹ̀ ẹ rẹ̀, í í ru ...
Read More »Ṣé Ìwọ mọ pé gbogbo agboolé nílùú Igbóọrà ní wọn ń bí ìbejì ?
Ṣé Ìwọ mọ pé gbogbo agboolé nílùú Igbóọrà ní wọn ń bí ìbejì ? Fẹ́mi Akínṣọlá Ṣé kò sí ìlú tí kò ní àdámọ́ ọ ti ẹ̀. Bẹ́ẹ̀ gẹ́lẹ́ lọ̀rọ̀ rí nílùú Igbóọrà .Igbóọrà jẹ́ ìlú kan tó kalẹ̀ si ...
Read More »Yẹ Kí Nàìjíríà Dín Iye Àwọn Sẹ́nétọ̀ Tó Ń Ṣojú Wọn Kù Tàbi, Ka Kúkú Pa Ipò Náà Rẹ́ – Fayemi
Ó yẹ kí Nàìjíríà dín iye àwọn Sẹ́nétọ̀ tó ń ṣojú wọn kù tàbi, ka kúkú pa ipò náà rẹ́ …..Gomina ìpínlẹ̀ Ekiti Fẹ́mi Akínṣọlá Ó ní àwọn sẹ́nétọ̀ tí ń náwó tó pọ̀jù léyìí tí Ìjọba yí le fi ...
Read More »Soworẹ́ Gbòmìnira Láhàmọ́ Ọ́ Dss Pẹ̀lú Ọgọ́rùn Ún Mílíọ̀nù Náírà
Soworẹ́ gbòmìnira láhàmọ́ ọ́ DSS pẹ̀lú ọgọ́rùn ún mílíọ̀nù náírà Fẹ́mi Akínṣọlá Èèyàn téégún ń lé,kó máa rọ́jú,bó ṣe ń rẹ ará ayé,náà ló ń rèrò ọ̀run. Àgbálọ gbábọ̀, ilé ẹjọ́ gíga t’ìjọba àpapọ̀ l’Abuja ti gba béèlì Omoyele Soworẹ́ ...
Read More »Ilééṣẹ́ Aṣọ́bodè Naijiria ń pa bílíọ̀nù N5.8 wọlé lójúmọ́
Ilééṣẹ́ Aṣọ́bodè Naijiria ń pa bílíọ̀nù N5.8 wọlé lójúmọ́ Fẹ́mi Akínṣọlá Ṣe n ta o ba fẹ ba fẹ o bajẹ, o ní ba a ṣe e ṣe e.N lo bi ọrọ kan ti ọ̀ga agba asọbode ilẹ yìí sọ ...
Read More »Ìjàpá Tó Wà Ní Ààfin Ṣọ̀ún Ògbómọ̀ṣọ́ (Alàgbà) Ti Papòdà
Ìṣe èèyàn ,ìṣe ẹranko, Ìjàpá tó wà ní ààfin Ṣọ̀ún Ògbómọ̀ṣọ́ Alàgbà ti papòdà lẹ́ni ojilelọọdunrun ọdún ó lé mẹrin lóke eèpẹ̀ . Fẹ́mi Akínṣọlá Toyin Ajamu, to jẹ akọwe agba ni Ààfin Kabiyesi Ṣọun ti ilẹ Ogbomọṣọ ti bùn ...
Read More »Àrùn burúkú fé̩ tú Queens college
Arun iba buruku kan n da yanpon- yanrin sile bayii ni ile-ise awon obinrin (Queens college) to wa ni ilu Eko.Ironu ti dori awon agba kodo ni ipinle Eko bayii paapaa julo fun gbogbo awon to lomo nibe. Ile-iwe yii ...
Read More »