Home / Tag Archives: Ede Oodua (page 10)

Tag Archives: Ede Oodua

Ìdí tí nó̩ḿbà ìdánimò̩ kò fi jé̩ dandan mó̩ – Àjo̩ JAMB

Ẹ kò nílò nọńbà ìdánimọ̀ NIN fún ìdánwò àṣewọlé ọdún 2020… Àjọ JAMB Fẹ́mi Akínṣọlá Ni báyìí Àjọ tó ń rí sí ìdánwò àṣewọlé ilé ẹ̀kọ́ gíga JAMB tí kó àfàró nípa lílo nọ́mbà ìdánimọ̀ “NIN” fún ìdánwò àṣewọlé ọdún ...

Read More »

Ẹ kéde iye ọlọ́pàá tó gba rìbá, kí ẹ tó má a yin ra a yín… Aráàlú sọ fún iléeṣẹ́ ọlọ́pàá

Ẹ kéde iye ọlọ́pàá tó gba rìbá, kí ẹ tó má a yin ra a yín… Aráàlú sọ fún iléeṣẹ́ ọlọ́pàá Èsì àwọn ọmọ Nàìjíríà tó tẹ̀lé bí iléèṣẹ́ ọlọ́pàá ṣe yin ara rẹ̀Lórí káàdì tí wọ́n fi síta lójú ...

Read More »

M C Oluo̩mo̩ fo̩wó̩ o̩lá gbáwa lójú – NURTW

MC Oluo̩mo̩ fo̩wó̩ o̩lá gbáwa lójú – NURTWLáti o̩wó̩ Yínká ÀlàbíOro ti gbogbo ara ilu ni o ti ku regbe ti o si ti di ohun igbagbe ni o tun n rugbo ni ibere ise yii laarin Musiliu Akinsanya ati ...

Read More »

Ìjọba ti ayédèrú ilé ọmọ aláìlóbìí pa, ọmọdé mẹ́tàdínlọ́gbọ̀n gbòmìnira

Ìjọba ti ayédèrú ilé ọmọ aláìlóbìí pa, ọmọdé mẹ́tàdínlọ́gbọ̀n gbòmìnira Fẹ́mi Akínṣọlá Àwọn aláṣẹ tọ́rọ̀ kan lórílẹ̀-èdè Nàìjíríà ti kó àgádágodo sílẹ̀kùn ilé ọmọ aláìóbìí kan tí kò ní wè é òfin ní ìpínlẹ̀ Kaduna, tí wọ́n sì tú ọmọdé ...

Read More »

Àwọn ará ilú dáná sún èèyàn méjì tí wọ́n furasí bíi olè

Àwọn ará ilú dáná sún èèyàn méjì tí wọ́n furasí bíi olè Ọjọ́ gbogbo n t’olè, ọjọ́ kan n tolóhun.Àwọn ènìyàn méjì kan ti wọ́n fura si gẹ́gẹ́ bi olè, ni wọ́n ti dáná sun nílùú Calabar, tíí ṣe olú ...

Read More »

Ẹgbẹ́ Shiites wọ́de l’Abuja, wọ́n jó Àsìá Amẹ́ríkà

Ẹgbẹ́ Shiites wọ́de l’Abuja, wọ́n jó Àsìá Amẹ́ríkà Egbìnrìn ọ̀tẹ̀, bá a se n pàkan, nìkan ń rúÀwọ́n ọmọ ẹgbẹ́ “Islamic Movement of Naigeria” (IMN) tí gbogbo ènìyàn mọ sí Shi’ites lọ́jọ́ ajé ti ya sí ìgboro lágbègbè ilé ìtajà ...

Read More »

Ẹjẹ yóó sàn, bí Amẹ́ríkà ṣe pa olórí ọmọ ogun un wa – lran

Ẹjẹ yóó sàn, bí Amẹ́ríkà ṣe pa olórí ọmọ ogun un wa..lran Kójú má ríbi , gbogbo ara lòògùn rẹ̀,bó ṣe jẹ́ pé, ó ń bọ̀ ,ó ń bọ̀ , gbogbo ara ní wọ́n mú tó o.À bí kí lọ̀rọ̀ ...

Read More »

È̩ ń fi ẹ̀wọ̀n run imú ẹ̀yin Olóyè Ìbàdàn mọ́kànlélógún tẹ ń ǹ pera a yín lọ́ba

Ọrọ̀ kò tíì tán lórí àwọn Olóyè mọ́kànlélógún tí Ilé ẹjọ́ sọ pé kí wọ́n lọ rọọ́kún nílé nílùú Ìbàdàn. Kọmíṣọ́nnà ètò ìdájọ́ tẹ́lẹ̀rí nípìńlẹ̀ Oyo, Ọ̀gbẹ́ni Michael Lànà ló ṣe ìkìlọ̀ fún wọn pé, kí wọ́n yé pe ara ...

Read More »

Àmọ̀tẹ́kùn: Ẹ̀ṣọ́ ilẹ̀ Oòduà (Yorùbá) ‘Àmọ̀tẹ́kùn’ ṣetán láti bẹ̀rẹ̀ iṣẹ́ káàkiri ilẹ̀ káàárọ̀ o ò jíire

Ọ̀rọ̀ ti di olójú ò níí yajú ẹ̀ sílẹ̀ kí tàlùbọ̀ ó yíwọ̀ọ́ àti pé ọmọ onílùú kò níí fẹ́ ó tú lọ̀rọ̀ dà báyìí ó, bí.

Read More »

Ohun t’ọ́kùnrin ń ṣe l’Ekiti, obìnrin lè ṣe é. Àjọ̀dún Àṣà ìbílẹ̀ lékìtì

Àṣà àti ìṣe wà nínú n tíí ṣàfíhàn èèyàn bí ọmọ ọkọ tàbí ọmọ ìdàkejì n ló díá fún bí onírúurú ohun tẹ́ ẹ̀ tilẹ̀ mọ pé ó wà láyé yìí se dohun àfojúrí níbi ayẹyẹ àjọ̀dún àṣà ọdún yìí ní ipinlẹ Èkìtì, .

Read More »