Ènìyàn o̩gbò̩n ti lùgbàdì coronavirus ni NaijiriaÌròyìn láti o̩wo̩ Yínká Àlàbí Afi ki Eledua maa ko wa yo ni orileede yii. Bi ere bi awada, ajakale arun kogboogun (covid-19) ti mu eniyan ogbon di asiko ti a n ko iroyin ...
Read More »Alárùn kòkòrò corona e̩lé̩è̩ké̩ta fara hàn
Arabinrin ti o sese ti ilu London de ni o bere si nii wuko ti o si n se kata. Ni eyi ti o mu ki o fara re sile fun ayewo coronavirus.
Read More »Ọ̀nà Jìbìtì
Bi ara ipede Radio Naigeria O.Y.O ni aye atijo, won ni, “Ifunra loogun agba, pasa ko funra, o ja sina, aja ko funra, aja jin, ti onile naa ko ba funra, ole ni yoo ko lo”. Eyi ni o difa fun gbogbo awa ti a maa n gbe moto lo si ibi inawo.
Read More »Àríwá Nàìjíríà, Ẹ Sọ Ẹran Jọ̀bọ̀jọ̀bọ̀ Nù Bí Ẹ Ṣe Yọ Sanusi – Soyinka
Ọ̀jọ̀gbọ́n Wọlé Soyinka ti bu ẹnu àtẹ́ lu bí Ìjọba ìpínlẹ̀ Kano, lábẹ́ ìsàkóso Gómìnà Abdullahi Umar Ganduje, lórí bó ṣe rọ Lamido Sanusi lóyè, gẹ́gẹ́ bí Emir ìlú Kano.
Read More »Fayemi, ilẹ̀ Oòduà (Yorùbá) kìí ṣe Kano tí wọn ti ń yọ Emir lórí oyè… Alaafin
Àwọn ọmọ Nàìjíríà lórí ojú òpó ìkànsíraẹni Twitter ti dásí ọ̀rọ̀ láàrin Gómìnà Ìpínlẹ̀ Ekiti, Kayode Fayemi àti àwọn ọba ní ìpínlẹ̀ náà. Èyí kò sẹ́yìn lẹ́tà tó jáde lórí ẹ̀rọ ayélujára níbi tí Aláàfin Ọ̀yọ́, Ọba Lamidi Olayiwola Adeyemi ...
Read More »Ado Bayero di Emir Kano
Adi Bayero di Emir Kano Ìdààmú ilé ọlá kan kìí rọ̀, ko ko ko níí le. Ní báyìí Ìgbìmọ̀ ìsàkóso Ìjọba ìpínlẹ̀ Kano ti rọ Emir Sanusi lóyè ní ọjọ́ Ajé, ọjọ́ kẹsàn án Oṣù kẹta ọdún 2020. . Ó ...
Read More »Ọba mẹ́wàá, ìgbà mẹ́wàá
Awon onpitan wu itan Emir Kano ana jade. Won ni oro re dabi egun ti baba baba re ti se sile. Won ni odun 1963 ni ede aiyede waye laare Emir Mohammed Sanusi to je baba eni ti gomina yo ...
Read More »Àwọn obìnrin tọ́kasí pàtàkì ìbáraẹnidọ́gba láárin ọmọnìyàn
Àwọn obìnrin tọ́kasí pàtàkì ìbáraẹnidọ́gba láárin ọmọnìyàn Ọjọ́ kẹjọ ọdọọdún ni àyájọ́ àwọn obìnrin lágbàáyé níbi tí gbogbo àgbáyé tí ń kọjú sí àwọn obìnrin láti yòǹbó àwọn iṣẹ́ takuntakun tí wọ́n gbé ṣe láì nọ́ọ́ní onírúurú ìpèníjà, ẹ̀dùn ọkàn ...
Read More »Ọ̀ràn dé! Alárùn coronavirus di méjì ní Nàìjíríà
Lara ayewo ti ijoba apapo ati awon ajo NCDC (Nigeria Centre for Disease Control) n se pelu awon ti won ba arakunrin ara orileede Italy wo baalu ati oko po. Won n se ayewo yii naa pelu awon ti won ...
Read More »Ganduje ti rọ Emir ìlúu Kánò, Sanusi Lamido Sanusi lóyè
Ganduje ti rọ Emir ìlúu Kánò, Sanusi Lamido Sanusi lóyè Ìdààmú ilé ọlá kan kìí rọ̀, ko ko ko níí le. Ní báyìí Ìgbìmọ̀ ìsàkóso Ìjọba ìpínlẹ̀ Kano ti rọ Emir Sanusi lóyè ní ọjọ́ Ajé, ọjọ́ kẹsàn án Oṣù ...
Read More »