Home / Tag Archives: Oduduwa

Tag Archives: Oduduwa

Odù kan gorí àtẹ,Ọdẹ́gbèmí Ọdẹ́gbolá11 goróyè Àràbà nílẹ̀ẹ̀bàdàn

Odù kan gorí àtẹ,Ọdẹ́gbèmí Ọdẹ́gbolá11 goróyè Àràbà nílẹ̀ẹ̀bàdàn Onírúurú aṣọ lára alágẹmọ, onírúurú ètè lápèjẹ sààráà lọ́jọ́ tí orí mádé, w nu agogo idẹ ní tií wà, ọrùn w’ọnú lèjígbà ìlẹ̀kẹ̀, àní lọ́jọ́ tó mú ìbàdì Àràbà Ògbó awo ,Oloye ...

Read More »

Ẹgbẹ́ Àwọn Àgbààgbà Oòduà Ní Osinbajo Kò Gbọdọ̀ Kọ̀wé Fipò Ẹ̀ Sílẹ̀

http://iroyinowuro.com.ng/2019/11/09/egbe-awon-agbaagba-yoruba-ni-osinbajo-ko-gbodo-kowe-fipo-e-sile/ Ẹgbẹ́ àwọn àgbààgbà Oòduà (Yorùbá) ní Osinbajo kò gbọdọ̀ kọ̀wé fipò ẹ̀ sílẹ̀ Fẹ́mi Akínṣọlá Èyí ò tófò, kò tófò,fìlà aráabí kù rébété, Kemi Adeoṣun lọ , orí ló kó Adebayọ Shittu yọ,tó fi rí sáa àkọ́kọ́ lò já.Ní ...

Read More »