Home / Tag Archives: ooni

Tag Archives: ooni

Ọ̀daràn kan fi tipá wọ ààfin Ọ̀ọni ilé ifẹ̀

Ọ̀daràn kan fi tipá wọ ààfin Ọ̀ọni ilé ifẹ̀ A kìí gbélé ẹni ká fi ọrùn rọ́ ni a ti ń gbọ́ tipẹ́ tipẹ́, sùgbọ́n kín wá ni ká ti pe tirúfẹ́ ìṣẹ̀lẹ̀ ajániláyà yìí tó wáyé ní ààfin Ọọ̀nirìṣà ...

Read More »

Igbeyawo Ooni Ile-Ife fo yangayanga?

*Oba Ogunwusi n mura lati se igbeyawo tuntun   Lose to koja ni awon aheso oro kan be sile nigboro eleyii to ti bere si ni mu awuyewuye lowo bayii. Lara awon oro naa ni eyi ti n wi pe, ...

Read More »

Won ti yan Ooni tuntun ni Ile-Ife

Awon afobaje ilu Ile-Ife ti yan Omooba Adeyeye Enitan Ogunwusi lati idile Giesi gege bi Ooni tuntun bayii. Won si ti fi oruko oba tuntun naa ranse si gomina ipinle Osun, ogbeni Rauf Aregbesola.

Read More »