Manchester united ti se tán láti ra Odion Ighalo pátápátá Lati owo Akinwale Taophic Se won ni ti egungun eni ba jo re, ori a ma ya atokun re. Ati wi pe, Ku ise ni n mu ori eni ya! ...
Read More »Ikú agbábó̩ò̩lù: LMC fa ìbínú yo̩
Ikú agbábó̩ò̩lù: LMC fa ìbínú yo̩– Iroyin lati Owo Akinwale Taophic. Latari iku odo agbaboolu, Chineme Martin’s, eni ti o pade iku ojiji ni abala akoko ifigagbaga ose ketalelogun liigi orileede wa Nigeria, NPFL, ti o waye laarin Nasarawa United ...
Read More »Sofia Kenin gba ife è̩ye̩ ìdíje Australia open 2030
Omo orileede American, Sofia Kenin, ti fi ebun re han si gbogbo agbaye pelu bi o se bori ifigagbaga asekagba laarin oun ati omo orileede Spain
Read More »“Idagbasoke awon akonimoogba gbodo je koko fun NFF” – Amodu
Shuaibu Amodu, okan lara awon igbimo oludari ajo NFF ti so wi pe ona kan pataki lati se igbelaruge fun ere boolu alafesegba abele ni nipa sise eto idagbasoke fun awon akonimoogba ere boolu ile Naijiria. Oro yii ni Amodu, ...
Read More »“E ma fi mi we Messi mo”- C. Ronaldo
Ogbontarigi agbaboolu Real Madrid, Christiano Ronaldo ti ro awon ololufe ere boolu agbaye lati dekun ati maa fi we akegbe re lati inu egbe agbaboolu Barcelona, Lionel Messi.Bi o tile je wi pe gbogbo awon ololufe ere boolu ki i ...
Read More »O se o Eledua ! Alaafia ti n pada sara Oliseh
Akonimoogba egbe agbaboolu Super Eagles, Sunday Oliseh, si wa ni ile iwosan niluu Belgium nibi to ti n gba itoju lowo. Iroyin tuntun to te Olayemi Oniroyin lowo lati enu awon dokita isegun oyinbo ti n toju re fi ye ...
Read More »