Home / Test2page 101

Test2

Iba Bambi Oluorojo arigba ota segun!

Arira mase fi ina re na mi o! Aase! A ku Ose Sango!   Cc- IyaOgbe OmoEdu Yeyelufe Oyewole‎

Read More »

Abi e roju aye bi?

Orewa nso fun ara ile wipe ki won Ba oun gbe orin, sugbon won o da loun, lo ba binu lo Si oko o da orin sugbon won o fun lounje, o tun lo si Odo o da orin won ...

Read More »

Ounje emi fun t’ooro yii ( 20 – 07 – 2016 )

HUN !!! # Odo to gbagbe # Orisun … Gbigbe nii gbe … WOO ORE WA !!! Ibi  Ipile eda L’orisun won.. Ibi  Eniyan ti lalehu ni Ipile re… Eni to bini ‪Orisun‬ eni nii se… ‪Eniyan‬ to wo’ni dagba ...

Read More »

Iyawo: mi o le gba ki iya oko mi gbe pelu mi lailai.

Olotu:kini ikan tori tofi ni o le gba ki iya gbe pelu re,gbogbo awon eyan loti ba e so,o ko,o loni gbo,won tun gbe e wa sori afefe,agidi yi nan lotun lo.Kini ikan to sele gan. Iyawo:seri olotu,mole gba ki ...

Read More »

Ewesooo Dede Ewen Goons Mi

Proudly IJEBU

Read More »

Olojo Ibi Toni

Mo layo lati so fun yin wipe oni ni ojo ibi Alfa Ola Akeem Totofun’un ti won je okan pataki ninu ebi Ooduarere. Olojo ibi oni a ki yin e ku ayo oni, e o se pupo re laye ninu ...

Read More »

Ojumo Ire

B’ojumo ba mo .. Ooye a la ‪#‎peregede‬.. A D’ifa fun Peregede tii se yeye ‪#‎Ojumo‬ . A KU OJUMO #Ojumo to mowa Lonii. ‪#‎Ojumo_Ire‬ gbogbo ni yoo je funwa lase Oba mi Oke .

Read More »

Elesin Oyan

Iba Orunmila Bara Agbonniregun; Elesin Oyan; Adagbaa Ojomu; Gbolajoko Omo Ere l’apa; Baba Okinkin ti n m’eyin erin fo; Odudu tii du ori emere ti o je ko fo; Atori eni ti ko sunwon se! Iba Baba o!

Read More »

Oniwowo ado! Baba dakun ma na mi o! Aase!

OBALUAYE!!!!!! OOOOOOO cc- Babalawo Ifakayode Oyedele Osaifa

Read More »

Foto ode’oni – 13.07.2016

Saheed osupa akorede ati baba wande.

Read More »