Ewi Toni: Atoto arere
Gbogbo omo Yoruba Ki gbogbo eye igbo pa lolo Etu to n numo lowo O ma lee numo Gbogbo Ekulu ko ma lee numo loka Omo Ade ti de to fe korin ogbon Akewi Imoran de to fe farofo sasaro ...
Read More »
Gbogbo omo Yoruba Ki gbogbo eye igbo pa lolo Etu to n numo lowo O ma lee numo Gbogbo Ekulu ko ma lee numo loka Omo Ade ti de to fe korin ogbon Akewi Imoran de to fe farofo sasaro ...
Read More »Ni akoko, mo sure fun toko-taya pe iku aitojo ko ni pa gbogbo wa o(ASE EDUMARE). …….. Ni aye atijo, ti oko ba tete ku, ti iyawo re si tun wa loju-opon, won o ba so pe ki aburo oko ...
Read More »E MAA WI TELE MI : …… *Sekere kii rode ibanuje, oro ibanuje koni je temi. *Tijo-tayo ni ti sekere, oro ayo ati idunnu ko ni tan ninu ile mi. *Ogun idile ko ni bori mi. *Ki osu yii to ...
Read More »Oruko mi ni IBINU, emi ko le fun wara, sugbon mo le da wara nu. Ise ti eniyan ba fi ogun odun ko jo, emi IBINU le fi iseju kan baaje. Sora fun emi IBINU ti o ba fe se ...
Read More ».( Ni gbongan adulawo ni Yunifasiti Afonja, awon eniyan n wole leni tere, eji tere. Won n gba tikeeti, won si n wole jokoo. Awon ti o fe safihan sinima naa n gunke, won nso. Won nfa waya, won gbaradi. ...
Read More »*Edumare ma fi omo pa mi lekun. *Oluwa ma fi mi pa omo mi lekun. *Ile alayo mi ko ni di ile ibanuje *Ogun aye ko ni bori mi. *Iji aye ko ni ja lu mi. *Ayo mi ko ni ...
Read More »