Home / Test2page 144

Test2

“Eyin ni agbara ati isegun mi l’Ojoosegun”: Ipinle Oyo gba leta Ajimobi

Olayemi Olatilewa Gomina ipinle Oyo, Abiola Ajimobi ti gbe sadankata fun awon eniyan ipinle Oyo fun atileyin ti won se fun un lati segun niwaju ile ejo to n risi awuyewuye eto idibo to waye lojo isegun to koja yii. ...

Read More »

Won Fadi Omo Odun Meji Ya Niluu Abuja

Olayemi Olatilewa Omokunrin eni odun merindinlogun (16) kan ti lo foju ba ile ejo niluu Abuja leyin asemase pelu omobirin, eni odun meji (2) kan. Iroyin yii lo jade nigba ti olupejo, ogbeni  Adama Musa, eni ti n soju ile ...

Read More »

Owo te awon omo egbe okunkun niluu Ado-Ekiti

Olayemi Olatilewa Awon akekoo meji ile iwe gbogbonise ti ijoba apapo (Federal Polytechnic) to kale si Ado-Ekiti ati maanu kan ti n tu foonu se ni agbegbe naa ni won ti ko lo si iwaju ile ejo Majisireeti pelu esun ...

Read More »

Ireti Odegbami ja sofo lati di aare FIFA agbaye

  OlayemiOlatilewa Bi o tile je wi pe ajo ere boolu ile Naijiria ti n fenu so wi pe gbagbaagba ni awon wa leyin agbaboolu to gba boolu metalelogun (23) sawon ni akoko ti n gba boolu fun orileede Naijiria, ...

Read More »

“Bilionu lona bilionu owo naira ni Mimiko dabaru ni ipinle Ondo” – Alagba egbe APC

Olayemi Olatilewa Alaga egbe oselu APC eka ti ipinle Ondo, ogbeni Isaac Kekemeke ti fesun kan Gomina Olusegun Mimiko to je omo egbe oselu PDP nipa wi pe owo bi tirilionu kan naira (N1 trillion) ni gomina ti je mole ...

Read More »

Ile ise Ologun seleri owo tabua fun eni to ba ri Boko Haram

Olayemi Olatilewa   Ile ise Ologun ile Naijiria ti se afihan foto awon ogbologbo alakatakiti esin Islam, Boko Haram bi ogorun (100) eleyii ti won on wa lati mu. Awon wonyii ni won se apejuwe won gege oloye agba  ti ...

Read More »

Foto Mercy Aigbe meje (7) to ta lenu bi ataare

Ti ija ba wa ni be, e je a pari kia. Awon Yoruba si bo won ni tomo eni ba daa kawi, kii se ka fi saya. Egan ni he, Mercy Aigbe ta lenu bee lodun yungbayungba.  Olayemi ti mo ...

Read More »

Awada Kerikeri: Awon ole meji ti won lo fo banki

Awon ole meji ja ilekun banki kan loru ojo kan, won si n si awon seefu wo. Ninu akoko, yugooti bi i meloo kan ni won ri nibo, kò s’ówó. Won to yugooti naa wo, o ti kan lenu. Won ...

Read More »

Erin jade lenu Ajimobi leyin to feyin Ladoja janle nile ejo

Erin ayo lenu gomina Abiola Ajimobi nigba ti won  pe e lori ago wi pe o ti feyin Adewolu Ladoja janle nile ejo. Gomina Abiola Ajimobi ni ile ejo ti n risi awuyewuye eto idibo gomina ti da lare eleyii ...

Read More »

Ooni tuntun wo ilu Ile-Ife tilu-tifon

Omooba Adeyeye Enitan Ogunwusi ti wo ilu Ile-Ife fun imurasile fun iwuye re ti o waye ni kopekope yii

Read More »