Home / Àṣà Oòduà / Awon egbe APC ti ko lati mu ileri won se #Our5K

Awon egbe APC ti ko lati mu ileri won se #Our5K

Nje e ti gbo?

Awon omo ile igbimo asofin agba l’Abuja ti won je ti omo egbe APC ti tako aba eleyii to wa nibamu pelu ileri ti Aare se lati maa san egberun marun-un owo naira (5K) fun awon odo ti ko nise lowo. Ileri yii ni aare se nigba eto iponlongo ibo. Sugbon bayii, awon omo ile igbimo asofin ti won je omo egbe APC ti da aba naa nu bi omi isanwo.

About oodua

Leave a Reply

Your email address will not be published. Required fields are marked *

*