Deji Akure ti won yo loye ti gbe Ijoba ipinle Ondo lo sile ejo
Leyin odun marun-un ti ijoba ipinle Ondo ro Adesina Adepoju loye gege bi Deji tilu Akure, oba ilu Akure nigba kan ri naa ti gbe ejo dide ni kootu lati gba ade re pada. Ojo kewaa osu kefa odun 2010 ...
Read More »
Àṣà Oòduà Àṣà Oòduà
