Ejò nlá kan (paramólè) tí won pa ní agbègbè mi láìpé ní àró yí.
Ní àárò yí nígbà tí mo ti setán láti ma lo sí ibi isé ni mo pàdé àwon ògbéni yí, tí won n yo látàrí wípé won pa ejò, tí mo rò wípé paramólè ni, tí won sì ti gbèrò ...
Read More »
Ní àárò yí nígbà tí mo ti setán láti ma lo sí ibi isé ni mo pàdé àwon ògbéni yí, tí won n yo látàrí wípé won pa ejò, tí mo rò wípé paramólè ni, tí won sì ti gbèrò ...
Read More »Amanda, tí ó n gbé ní Atlanta tí ó jé ìyá omo olórin orílè èdè Nàíjíríà, Davido, pin sí orí ìtàn èro ayélujára (insta-story)láti se ayeye ojó ìbí Davido nígbà tí ó pé odún márùnlélógún.
Read More »Gégé bí Sani tí ó pin se so, àwon èèyàn Bachama ní alé àná ti dojú ìjà ko àwon fúlàní ní ilé tí won ngbé ní Kwadam Shafaran ìlú kéréje kan ní Numan ti ìpínlè Adamawa. Ó kéré jù márùnlélógójì ...
Read More »Òkan l’ára àwon isé rè ni wípé tí ó bá ti e ò bá ti è níìfé orin rè èèyàn le níìfé àyà rè, bí kò tilè ní ìkan míràn jù béè lo, ó sáà ní àyà(6 packs) ...
Read More »Okò tí ó kó kírètì Coca Cola ni ó dànù ní òpópónà 3rd mainland bridge yí ó sì wó òpò kírètì àti ìgò ní orí afárá náà. Okò náà tún kolu okò kan tí a mò sí Toyota Corolla kí ...
Read More »Láìpé ni BankyW àti Adesua Etomi se ìgbéyàwó ìbílè won ní ìlú èkó, àwon tokotayà ti wá t’owó bo ìwé èrí ìgbéyàwó wo, won ti di oko àti aya . Won ti se ìgbéyàwó alárédè báyìí. Èyí da ...
Read More »A gbó láìpé la gbó wípé Wizkid ti kí omo tuntun káàbò tí alákoso rè, Jada Pollock bí fun. Òótó ni èyí, Wizkid ti ri dájú wípé omo òun ni , ó sì ti so omo náà l’órúko “Zion ...
Read More »9Ò n lò èro ayárabíàsà (Twitter) tí a mò sí Halima ni òpò ti takò látàrí wípé ó so wípé ó ye kí won gba obìnrin náà láyè kí won fé ju okùnrin kan lo. Ní òtító olórun ...
Read More »Òsèré tí ó gbajúgbajà, Adesua Etomi tún yo ní àrà òtò, sé e mò wípé òtò l’omo oba n rìn . Ó ti è ti rewà jù òun gan ni a ò bá ma pè ní Òkín l’áwùjo ...
Read More »Tani Aso yí dára jù lára rè láàrin àwon arábìnrin arewà méwàá yí. E rò ó e tó mú o, Beverly Naya rewà púpò, Stephanie rè é ojú kò kúrò lára rè, Toyin Abraham dàbí egbin ní tirè, Juliet kò ...
Read More »