Flavour ti fi èbùn olórun hàn l’ára rè nínú àwòrán tí kò ti wo aso tí ó yà.
Òkan l’ára àwon isé rè ni wípé tí ó bá ti e ò bá ti è níìfé orin rè èèyàn le níìfé àyà rè, bí kò tilè ní ìkan míràn jù béè lo, ó sáà ní àyà(6 packs) ...
Read More »
Òkan l’ára àwon isé rè ni wípé tí ó bá ti e ò bá ti è níìfé orin rè èèyàn le níìfé àyà rè, bí kò tilè ní ìkan míràn jù béè lo, ó sáà ní àyà(6 packs) ...
Read More »Okò tí ó kó kírètì Coca Cola ni ó dànù ní òpópónà 3rd mainland bridge yí ó sì wó òpò kírètì àti ìgò ní orí afárá náà. Okò náà tún kolu okò kan tí a mò sí Toyota Corolla kí ...
Read More »Láìpé ni BankyW àti Adesua Etomi se ìgbéyàwó ìbílè won ní ìlú èkó, àwon tokotayà ti wá t’owó bo ìwé èrí ìgbéyàwó wo, won ti di oko àti aya . Won ti se ìgbéyàwó alárédè báyìí. Èyí da ...
Read More »A gbó láìpé la gbó wípé Wizkid ti kí omo tuntun káàbò tí alákoso rè, Jada Pollock bí fun. Òótó ni èyí, Wizkid ti ri dájú wípé omo òun ni , ó sì ti so omo náà l’órúko “Zion ...
Read More »9Ò n lò èro ayárabíàsà (Twitter) tí a mò sí Halima ni òpò ti takò látàrí wípé ó so wípé ó ye kí won gba obìnrin náà láyè kí won fé ju okùnrin kan lo. Ní òtító olórun ...
Read More »Òsèré tí ó gbajúgbajà, Adesua Etomi tún yo ní àrà òtò, sé e mò wípé òtò l’omo oba n rìn . Ó ti è ti rewà jù òun gan ni a ò bá ma pè ní Òkín l’áwùjo ...
Read More »Tani Aso yí dára jù lára rè láàrin àwon arábìnrin arewà méwàá yí. E rò ó e tó mú o, Beverly Naya rewà púpò, Stephanie rè é ojú kò kúrò lára rè, Toyin Abraham dàbí egbin ní tirè, Juliet kò ...
Read More »Arábìnrin tí ó rewà tí ti jé kí elénu sónu níbi aso tí ó wò tí ó dùn tí ó sì tún se òwón (n se ni ó dàbí eni wípé ó wo bùbá àti ìró)ó wò lo sí ìbí ...
Read More »Okùnrin yí ni ó te omú obìnrin yí tí ó sì jé kí òpò ma sòrò . E gbó kí ló n selè níbi àwòrán yí? Mo ti è rò wípé arábìnrin yí kò ní gbà fún arákùnrin yí, okùnrin ...
Read More »Àwòrán Olusegun Obasanjo tí ó yà ní ìgbà tí ó ti pé tí ó yà ní kété tí won fi sílè ní èwòn. Olusegun Obasanjo níbi ìsìn ìdúpé léyìn ìgbà tí won da sílè l’éwon ní odún 1998. Owó mà ...
Read More »