Tiwa Savage gbégbà orókè níbi àmì èye AFRIMA 2017 tí ó sì gba èye náà mó Yemi Alade lówó .
Òdóbìnrin olórin àkókó ní ikò Marvins , Tiwa Savage gbé igbá orókè ní ibi àmì èye AFRIMA ti odún yí gégé obìnrin àkókó ní ikò adúláwò ti odún yí. Tiwa Savage pa Yemi Alade, Aramide àti Seyi Shey ...
Read More »