Ààre Buhari ní ìpínlè Anambra fún ìpolongo Dr. Tony Nwoye fún àwon omo egbé APC.
Ààre Buhari ní ìpínlè Anambra fún ìpolongo Dr. Tony Nwoye fún àwon omo egbé APC.
Read More »
Ààre Buhari ní ìpínlè Anambra fún ìpolongo Dr. Tony Nwoye fún àwon omo egbé APC.
Read More »Òdóbìnrin òsèré yí, Regina Daniel ti gbe lo sí orí ìtàn èro ayélujára (insta-stories) láti pín àwòrán tí ó ti yàtò yí.
Read More »Ìyá omo olórin flavour, Sandra tàtúù orúko rè “Chinedu” sí apá .
Read More »Èrín pa mí, ajá mi, pitbull pa á lónìí , ta ló fé?
Read More »Odára àbí kò dára?
Read More »Èyí ni ìsèlè tí ó selè láìpé ní ojó kejìlá osù kokànlá odún yí ní Gombe ní ìpínlè Gombe tí tírélà fà . lóòtó kò sí eni tí ó kú, sùgbón òpò ni ó se Lése gan. A ...
Read More »Adérìnpòsónú, Akpororo àti ìyàwó rè Josephine se ayeye odún kejì ìgbéyàwó won.
Read More »Báyìí ni adérìnpòsónú AY tí ó sèsè dé láti Dubai fún ìsinmi pín àwòrán òun àti Gómìnà ìpínlè Imo, Rochas Okorocha nígbà tí ó lo ki n’ílé, tí àwon olólùfé rè sì so wípé ère ti è náà kò ...
Read More »Wón ti so síwájú télè wípé àwon olópàá Nàíjíríà n sisé takuntakun láti só agbègbè Apogbon bridge tí a mò fún àwon dánàdánà.
Read More »Omokùnrin odún méwàá (10yrs) yí láti ìpínlè Anambrah ní orílè èdè Nàíjíríà , òun ni ó kó ilé yí orúko rè ni Chinecherewu. Mi ò le fun ní owó lásán ” ó n’ílò kí gbogbo ayé rí èyí.
Read More »