D’banj lo kí asojú ilé ìgbìmò asòfin Dino Melaye .
D’banj lo kí asojú ilé ìgbìmò asòfin ni ó pín àwòrán yí “koko master náà ni”.
Read More »
D’banj lo kí asojú ilé ìgbìmò asòfin ni ó pín àwòrán yí “koko master náà ni”.
Read More »Asojú ilé ìgbìmò asòfin Melaye ti tako Gómìnà ìpínlè Kogi Yahaya Bello tí ó gbèrò láti wó ilé rè ní ìpínlè Kogi. E kàá dáadáa.
Read More »Bí mo se ri ní orí èro ayélujára (Instagram), mi ò ti è mo ohun tí mo fé so, sé Techno sì ma san owó èyí bí.
Read More »Ogún-l’ógbòn àwon eléré orí ìtàgé ni ó n fi tipátipá béèrè ìbálòpò lówó àwon èèyàn láti le jékí won hàn nínú eré ti orílè èdè Nàíjíríà (Nollywood) gégé bí ìyá kan àti eni tí ìsèlè yí selè sí se ...
Read More »Àwòrán ògbó-n-ta-rì-gì olórin ní orílè èdè Nàíjíríà, Fela Anikulapo kuti àti agbejórò rè. Gbajúgbajà agbejórò tí ó tún jé bàbá ìlúmòóká olórin Falz d bahdguy ògbéni Femi Falana àti bàbá Beko Ransom Kuti . Mo gbàgbó wípé òrò ilé-ejó ni ...
Read More »Àwòrán tí ó gba èro ayélujára kan ti àmì èye south African Feather ti odún yi ni ìmúra àwon èèyàn kò bójúmu rárá. Olórin kan ní South African “Skolopad” wo aso tí ó kún fún sósèjì àti àpò èédú ...
Read More »Gégé bí ó ti pin sí orí èro ayélujára (Instagram). ” Nígbà tí o bá parí ìdánwò, tí o wá n padá li sí ilé , tí o wá kó sínú súnkere fàkere oko, wà sà ya àwòrán, mo ...
Read More »Ààre Muhammadu Buhari ti lo rí àwon omo egbé Christian Association of Nigeria (CAN ) ní ilé ìgbìmò ní ìlú Abuja.
Read More »Ìsinmi tòtè yí mà yàtà gan o, ó ti è ti dùn jù …járá oko yí mà da gan ni oo . Àwòrán obè aláta yéríyérí n bò láìpé.
Read More »Níbáyìí, ojú wo ni òrékùnrin rè ma fi wò ó tí ó bá rí ìdí òdóbìnrin yí?. Àwòrán tí ó ti gba èro ayélujára kan ni ti obìnrin tí ó ko orúko Runtown gangan sí ìdí rè. Olórin ...
Read More »