Gbajúgbajà òsèré, Mercy Aigbe pín ìròyìn ìbànújé.
Òsèré, ìyá, àti oní káràkátà ti pín aí orí èro ayélujára láti polongo wípé bàbá òun ti dágbére f’áyé.
Read More »
Òsèré, ìyá, àti oní káràkátà ti pín aí orí èro ayélujára láti polongo wípé bàbá òun ti dágbére f’áyé.
Read More »Omokùnrin Tiwa Savage, Tunji ‘Tee Billz Balogun ti è ti rewà jù. Gbajúgbajà olórin Tiwa Savage pín àwòrán omo rè tí ó rewà, Jamil Balogun nàà yo ní àrà òtò nínú aso aláwò pupa tí ó yí orùn ká.
Read More »Àare Muhammadu Buhari ti se ìbúra fún akòwé ìjoba gbogboogbò tuntun tí ó n jé Boss Mustapha . Ayeye ìbúra náà wáyé ní yàrá ìgbìmò Ààre.
Read More »Gégé bí ò n lò èro ayélujára tí ó gbé ní Yola tí ó pín ìròyìn ìsèlè yí se so, olópàá tí àwòrán rè hàn ní ìsàlè yí ní won yà nígbà tí ó n GBA owó èyin ...
Read More »Omokùnrin Terry G, Teerex pé omo odún Márùn-ún bàbá rè sì se ayeye ojó ìbí náà fun pèlú àwon òrò tí ó dùn tí ó pín sí orí èro ayélujára (Instagram).
Read More »Cossy Orjiakor tí a mò wípé óní àyà ni a ti gbó tí ó ti kérora nípa ìdí rè tí ó kéré lénu ojó meta yí, sùbón báyìí ó ti lo sí ilé-ìwòsàn láti sisé abe kí ìdí ...
Read More »Àwòrán àwon tokotaya tuntun, kí olórun fún won ní adùn ìgbéyàwó . Èyí ò wa rewà bí…
Read More »Gégé bí Timaya se pin sí orí èro ayélujára(Instagram) tí ó sì wípé . ” omo mi ti dé pèlú àrà òtò, gbogbo ìgbà ni ó ma n mú orí mi wú. PATORANKING mo féràn re ….
Read More »‘Okrika’ ni ònà tí àwon ènìyàn Nàjíríà n gbà pe aso tí won ti wò rí, tí won sí wo ìlú. Nígbà tí àwon nkan ti sa èyí tí ó dára níbè àwon kan kò ní aso tí won ...
Read More »Gbajúgbajà òsèré, Omoni Oboli àti oko rè Nnamdi se ayeye odún métàdínlógún ìgbéyàwó won. Won sì pín àwòrán tipétipé won…
Read More »