Omokùnrin Amanda Ebeye se ayeye odún kan ojó ìbí rè.
Ìyá tí inú rè n dùn pín àwòrán òun àti omokúnrin rè sí orí èro ayélujára (Instagram) tí ó sì ko síbè wípé ” kú ayeye ojó ìbí rè omo Mi…..Ayé mi ….Enìkejì mi…. Eni tí ó ...
Read More »
Ìyá tí inú rè n dùn pín àwòrán òun àti omokúnrin rè sí orí èro ayélujára (Instagram) tí ó sì ko síbè wípé ” kú ayeye ojó ìbí rè omo Mi…..Ayé mi ….Enìkejì mi…. Eni tí ó ...
Read More »Èmi ma le àpótí mo…
Read More »Síwájú Hushpuppi bú òré rè tí ó so wípé kò ní owó lówó lórí èro ayélujára (Instagram). Hushpuppi fi èsùn kàn án wípé ó n bá àwon omobìnrin Chinese tí kò to sùn. Àwòrán Mompha re, pèlú àwon ...
Read More »Arewà tí ó bí omokùnrin méji ni ó pín àwòrán òhun àti ìkan lára omo rè méjì sí orí èro ayélujára (Instagram). “Won n bínú wíwà l’áyé wa Tí ó sì jé wípé àwon ni won sún mó ...
Read More »Òkan lára àwon olólùfé Wizkid ni ó ya tàtúù ojú Wizkid àti logo starboy sí èyìn rè…
Read More »Àwòrán ègbón Davido, asojú ilé-ìgbìmò asòfin ní bi tí ó ti n jó láàrin àwon arewà…
Read More »Arákùnrin ará Cameroon ni ó fi igi oparun gbé kúlà yí, eléyìí tún ya ni lénu ooo…ogbón kìí pé ní ilé ayé sha…
Read More »Ní àárò ojóbò, ojó kerìndílógún osù kèwá, (26/10/2017) ilé-ìwé Obafemi Awolowo University (OAU) àti agbègbè rè pàdánù omo ilé-ìwé kan tí ó n jé Afolarinmi Mercy tí ó wà ní ìpele àkókó (100level) ní eka èkó Micro biology…
Read More »Ìyá omo Runtown, Selena leath pín sí orí èro ayélujára àwòrán sáájú àti léyìn òun àti Runtown pèlú omokùnrin won, Zamar…
Read More »À béè rí nkan, e ri bí won se se jómúrégí papò! Won bá ara won mu gan ni…
Read More »