Home / Test2page 73

Test2

Selena leath pín àwòrán sáàjú àti léyìn òun àti Runtown àti omokùnrin won.

Ìyá omo Runtown, Selena leath pín sí orí èro ayélujára àwòrán sáájú àti léyìn òun àti Runtown pèlú omokùnrin won, Zamar…

Read More »

Nínú agbami ifè ni won wà, gbajúmò òsèré Mode Funmi Martins àti oko rè Afeez Owo fi ìfé won hàn.

À béè rí nkan, e ri bí won se se jómúrégí papò! Won bá ara won mu gan ni…

Read More »

Àwòrán tí ó ti pé ti gbajúgbajà òsèré Odunlade Adekola.

     Àwòrán ìgbà èwe ni ní tòótó fún gbajúgbajà òsèré Odunlade Adekola. Táà bá ní pa iró owó dáa l’ára…

Read More »

Òdóbìnrin orílè-èdè Nàíjíríà kan se ayeye ojó ìbí rè tí ó sì há oúnje fún àwon aláìní.

    Òdómobìnrin orílè-èdè Nàíjíríà ni ó pinnu láti se ayeye ojó ìbí ní àrà òtò, nígbà tí a ri tí ó n pín oúnje àti àwon nkan míràn fún àwon aláìní, omodé àti àwon èèyàn míràn . ònà ni ...

Read More »

Oba Orin Sunny Ade àti Flavour Jo hàn ní orí ìtàgé.

     Oba orin Sunny Ade àti Flavour dìjo dá àwon ènìyàn l’ára yá lórí ìtàgé. Pèlú èrín ojú Flavour n se ni ó dà bí eni wípé inú rè dùn láti pàdé oba orin…

Read More »

Olùsó àgùntàn David Ibiyeomie gba okò bògìnì fún èbùn ojó ìbí rè nígbà tí ó pé odún márùnléláàdóta .

     Gégé bí Innocent se so, olùsò àgùntàn rè pastor David Ibiyeomie ni won fún ní okò bògìnì tí ó wà ní ìsàlè yí gégé bi èbùn ojó ìbí rè, sé kò dùn gbó l’étí ni?. Ó ye kí ...

Read More »

Òrò ni *IFÁ*.

    Òpolopò ènìyàn ni kò mo ìyàtò láàrin *IFÁ àti OLÓDÙMARÈ*. Òrò ni ifá, èyí tí ó ti enu Olúdùmarè wá tí ó fi rán *ÒRÚNMÌLÀ*

Read More »

Mike Ozekhome se ayeye ojó-ìbí rè nígbà tí ó pé ogóta odún(60).

Gbajúgbajà amòfin oloyè Mike Ozekhome, SAN se ayeye ojó ìbí rè nígbà tí ó pé ogóta odún ni ilé-ìtura Sharaton tí ó wà ní ìlú Abuja nínú àwon tó lo ni Ààre télè Goodluck Jonathan, ìyàwó rè Patience, igbákejì Ààre ...

Read More »

Ewo nkan tí àwon èèyàn se fún àwon olè meta tí won jí kòkò obè.

Gégé bí ò n lò èro ayélujára( Facebook) tí ó pin àwòrán àwon òdókùnrin méta yí tí a gbó wípé won sì wà ní ilé-èkó girama ni won fi ìyà je won tí won sì so won kó sí ojú ...

Read More »

Awakò okò epo NNPC pa arákùnrin kan ní Aba.

     Gégé bí Sopu tí ó n gbé ní Aba se so, olóògbé tí àwòrán rè hàn n’ísàlé yí ní awakò okò epo ti NNPC pa. Òpòlopò ènìyàn sì péjo láti ya àwòrán rè láti jé kí àwon mòlébí ...

Read More »