Ìyà tí òyìnbó fi je ìran Yorùbá kò kéré.
Bí ó bá jé ti erú tí won kó wa ni kì bá da, bí kò se ikú burúkú tí won fi n pa àwon baba nlá wa. Béè won kò dá owó dúró. Kí Elédùmarè gbà wá lówó ...
Read More »
Bí ó bá jé ti erú tí won kó wa ni kì bá da, bí kò se ikú burúkú tí won fi n pa àwon baba nlá wa. Béè won kò dá owó dúró. Kí Elédùmarè gbà wá lówó ...
Read More »Yannick Arnauld Engolo láti orílè èdè Cameroon tí ó sì jé ènìyàn Swiss tí ó dá Miscas àti priceless corporation sílè ni a ti fi èsùn kàn látàrí wípé ó pa àwon omo rè méta. Ó ti è pe ...
Read More »Àwon omo egbé òkùnkùn Eiye àti Àíyè ti so wípé àwon kò se mó nígbà tí won se ìwóde gbangba ní ìpínlè Èkó.
Read More »Olga, ìyàwó ògbóntàrigì agbá bóòlù Mikel Obi, pín àwòrán ara rè nígbà tí ó n bá àwon omo rè seré , tí ó sì n ka ìwé fún won .
Read More »Ààre ilé-ìgbìmò asòfin Bukola Saraki pàdé Akòwé ìjoba gbogbogbò tuntun (SGF)Boss Mustapha.
Read More »Dr. Akinwumi Ambode, Gómìnà ìpínlè Èkó se ayeye láti we okò ojú omi tí ó sèsè rà, okò ojú omi náà sì wà fún ìpínlè Èkó, bí ó se so wípé àwon n sisé láti jé kí ìrìnàjò orí omi ...
Read More »Àwon akékojáde ti ilé-ìwé giga Calabar (UNICAR) se ayeye ìkékojáde won ní àrà òtò. ” kò rorùn béè ni kò lera …ayò ni a ka gbogbo rè sí!!!”òkan nínú won ni ò pín èyí sí orí èro ayélujára (Facebook).
Read More »Olópàá tí ó n sojú àgó olópàá Domping ní orílè èdè Ghana, Ase Emmanuel Osei ni won ti fi èsùn kàn látàrí wípé ó fi pàsán na arábìnrin odún mókàndílógbòn (29) tí a mò sí Sarah Darko ní ...
Read More »Òsèré, ìyá, àti oní káràkátà ti pín aí orí èro ayélujára láti polongo wípé bàbá òun ti dágbére f’áyé.
Read More »Omokùnrin Tiwa Savage, Tunji ‘Tee Billz Balogun ti è ti rewà jù. Gbajúgbajà olórin Tiwa Savage pín àwòrán omo rè tí ó rewà, Jamil Balogun nàà yo ní àrà òtò nínú aso aláwò pupa tí ó yí orùn ká.
Read More »