Home / Test2page 80

Test2

Gómìnà Yahaya Bello ri èro amúnáwà (Transformer) gégé bí isé rè àkókò ní ìpínlè Kogi. 

Gégé bí ìròyìn se so, Gómìnà ìpínlè Kogi: Yahaya Bello ri èro amúnáwà tí agbára rè tó Egbèédógún (300KVA) ní òpópónà kan ní Lokoja gégé bí isé rè àkókó léyìn tí ó ti lo odún kan àti ààbò lórí ipò. ...

Read More »

Owó te olùsó àgùntàn(pastor) èké kan nígbà tí ó ń gbìyànjú láti ri ohun tí a kò mò sí ilé onílé. 

Olùsó àgùntàn èké kan tí a mò sí Osinachi Christopher láti ìpínlè Abia ni won fi s’èsín léyìn ìgbà tí owó ti tèé nígbà tí ó ń gbìyànjú à ti ri ohun tí a kò mò sí ilé onílé ní ...

Read More »

Ilé ejó gíga jù dá asòfin ìpínlè Taraba dúró, tí orúko rè ńjé Sani Danladi

Won pàse fun kí ó dá owó osù àti àláwánsì tí ó gbà. Ilé ejó gíga jù ti pàse fún asòfin tí ó ń sojú ilé asòfin àgbà àríwá ti ìpínlè Taraba sani Abubakar Danladi láti fi ipò náà sílè ...

Read More »

Àwon Agbófinró ìpínlè Èkó so ònà tuntun tí àwon gbómogbómo ńgbà jínigbe. 

Àwon Agbófinró ìpínlè Èkó so ònà tuntun míràn tí àwon gbómogbómo ńgbà jínigbe. Ní ìsàlè ni òrò tí agbenuso àwon Agbófinró ìpínlè Èkó, SP Dolapo Badmos so. “E jò ó tí enikéni bá fi káàdì ìpè ráńsé sí yín tí ...

Read More »

Àwon ológun yín ìbon lu omokùnrin odún márùn-ún ní Kaduna nígbà tí won ń ké ìrora won ní rowérosè ..

Gégé bí omo oòduà rere se so, omokùnrin odún márùn-ún tí orúko rè ńjé Hussein Mustapha ni àwon ológun yin ìbon lu nígbà tí won ń ké ìrora (rally) ní Kaduna láti fi àmì sí Qusday ní àgbáyé láti gba ...

Read More »

Àwòrán; Toke Makinwa  jáde ní àrà òtò ní orílè èdè South Africa láti pàdé SA OAP àti àwon t’ókun lórí àjò SA tí ó ń bò lónà. 

Toke Makinwa sèsè dé sí orílè èdè South Africa láìpé yí gégé bí ó se ń rìn káàkiri àgbáyé láti di gbajúgbajà ònkòwé.  Ìmúra rè yanilénu nígbà tí ó wo aso aláwò   pupa férééfé (pink Gert Johan) àti bàtà ...

Read More »

Gómìnà Nyesom Wike dá òkan lára àwon Konmisôna rè dúró. 

Gómìnà ìjoba ìpínlè River, Nyesom Wike ní òwúrò yí dá Konmisôna isé dúró ní ìpínlè rè tí orúko rè ńjé Bathuel Harrison (àwòrán eni tí ó wo jákèètì).  Nínú òrò tí olùrànlówó pàtàkì rè so lórí ìtànná ohun Ìgbéròyìn jáde ...

Read More »

Díè nínú ìsesí láti òdò Dino Melaye lórí ìròyìn èrò rè tí a se ìrántí láti ìgbìmò asòfin àgbà. 

Ní àná, ìgbìmò tí ó ń darí ètò ìdìbò (INEC) gba àpò méfà tí ó kún fún ìbowólù àwon tí ó tó láti dìbò ní agbègbè Eokun ìwò oòrùn ní ilè Kogi, tí ó ń bèèrè fún ìrántí Dino Maleye ...

Read More »

Ipò Burúkú Ti Ilé-ìwòsàn Ńlá Ní Warri Ní Ìjoba Ìpínlè  Delta Wà. 

Èyí ni ìròyìn ipò tí ilé-ìwòsàn ńlá wà ní warri ní ìjoba ìpínlè Delta wà lówólówó . Àwòrán na jé pínpín sí orí èro ayélujàra (facebook) English Version Continue after the page break

Read More »

Ilé Tí Won Ń Kó Lówó Wó Ní Ilorin. 

Èrù ti ń ba àwon òpòlopò ènìyàn bóyá àwon ènìyàn kú sí inú ilé tí won ń kó lówó ní òpópónà Stella, Tanke ,Ilorin ,ní ìjoba ìpínlè Kwara tí ó wó ní òsán yí. English version Continue after the page ...

Read More »