Home / Àṣà Oòduà / Ìjọ Ọ̀rúnmìlà Ifákáyéjọ afi òtítọ́ ayé hàn

Ìjọ Ọ̀rúnmìlà Ifákáyéjọ afi òtítọ́ ayé hàn

Àwa ni ìmọ́lẹ̀ fún gbogbo Ìjọ mímọ́ Ọ̀rúnmìlà ní gbogbo àgbáyé nítorí ọ̀rọ̀ Ọlọ́run tí àńpè ní Ifá ni a fín to Ìjọ tiwa

Ifá(ọ̀rọ̀ Ọlọ́run)ni afi kó ayé jọ
Ọ̀rúnmìlà(aṣíwájú rere)ní abá ni táyése

Ẹ wá bá ọ̀rọ̀ ẹnu Ọlọ́run tí àńpè ní Ifá pàdé nínú ìjọ wa, kí ìtumọ̀ sí bá ìgbésí ayé rẹ lọ́dún titun

Awóyemí Ọlọ́run wà 1
Ṣókinlójú arẹ̀mọ ẹ̀dú
Aníkin ajé níkùn 1
Small but mighty
CEO Gbasky bitter

Mo sé ní ìwúre sí Ọlọ́run fún orí kọ̀ọ̀kan wa lókùnrin lóbìnrin lọ́mọdé àti àgbàlagbà wípé gbogbo oun tó sokùnkùn nínú ayé wa,pẹ̀lú àṣẹ Olódùmarè ìmọ́lẹ̀ yóò tàn nínú ọdún titun,okùnkùn yóò sì wábigbà

About ayangalu

x

Check Also

“Ta Ní Ó Wà Kí Ayé Tó Wà? Ìtàn Àkọ́kọ́ Ìṣẹ̀dá Gẹ́gẹ́ Bí Ifá Ṣe Sọ Ó.”

Kò sí ohun ẹlẹ́mìí kankan láyé awo ilé Ayé ni ọ̀run àkọ́kọ́, ohun tí ó so kàrà tí kò sọ̀kalẹ̀, awo òde Ọ̀run ni ó ń pè é, gbogbo rẹ̀ jẹ́ òfìfo lásán, òfo pónbele, láìní ìpìlẹ̀, láìní ẹ̀dá kankan, Awo àárín gbùn-gbùn òde ni ó wí i, A dífá fún Ayé àti fún Ọ̀run, nínú ìkarawun ìgbín méjì tí ó ṣófo, kò sí ẹyẹ, kò sí ẹ̀mí tí ń gbé inú wọn, ìpìlẹ̀ kò tí ì sí, afẹ́fẹ́ kò ...