Home / Tag Archives: ifa (page 4)

Tag Archives: ifa

Odu Ifa Iwure Toni Ki Bayi Wipe…

Ekaaro eyin eniyan mi, aojiire bi? Aku ise ana o, oni a sanwa sire gbogbo o ase. Odu ifa iwure toni ki bayi wipe: Òkan fìkìkìkì babalawo oladeji difa fun oladeji eyiti won nfojojumo njuwe re fun iku, won ni ...

Read More »

Ijinle Ninu Oro Ifa Fi Ye Wa Nipa Bi Ila Se De Atelewo Wa.

Ekaaro eyin eniyan mi, aojiire bi? Ojó oni a san wa o ao ri tiwa se o ase. Gegebi awon opolopo eniyan se maa nsoro wipe “atewolabala ao meni to ko” lotito la ba ila latelewo wa sugbon imo ijinle ...

Read More »

Ifa Iwure Toni Jade Ninu Odu Ifa Ogundigara

Ekaaro eyin eniyan mi, aojiire bi? Aku aseku odun o emin wa yio se pupo re laye awon alaseku yio bawa se o, ako ni rogun inira o ase. Ifa iwure toni jade ninu odu ifa Ogundigara Ifa naa ki ...

Read More »

Odu Eji Ogbe

Ìpẹpẹrẹ ìmọ ni farabalẹ ni jogunda Adia fun Orunmila Ifa nlọ ba wọn mulẹ budo Nita Iku nita Arun, Nita Ajogun Mẹrẹrindilogun Te nbẹ lode oṣalaiye. Slender-Palm-Frond-is-Patient-In-Taking-Its-Revenge Revealed the way to Orunmila when he was looking for a place to ...

Read More »

Ará Ọ̀run

Cc – Moyo Okediji

Read More »

Ifa naa ki bayi wipe…

Ekaaro eyin eniyan mi, aojiire bi? Aku ise ana o, a sin ku isimi opin ose, eledumare yio saanu wa o ao ri tiwa se loni, iyan jija koni ranwa lo sibiti ako fe o ase. Odu ifa ogbeweyin ni ...

Read More »

Ifa Toni Ki Bayi Wipe

Ekaaro eyin eniyan mi, aojiire bi? Aku ise ana o, oni a san wa o, eledumare yio gbo ohun ebe adura wa o ase. Ifa toni ki bayi wipe: Orunmila ni ori a lana kan Moni ori a lana kan ...

Read More »

Today’s Sermon – (Ijo Orunmila Ato) inc, Taken From Ejiogbe

My sermon today, Sat.3rd Sept. 2016 at our House of Worship, Indigene Faith of Africa( Ijo Orunmila Ato)Inc, taken from Ejiogbe:-   Akole/ Theme Iwa onikaluku la o fi da l’ejo By their characters shall they be judged Isepe werewere ...

Read More »

Odu Ifa Ose Meji/ Ose Olubadan

|   | | | | | |    | | | | | Ekaaro eyin eniyan mi, aojiire bi? Aku ise ana o, a si tun ku orire osu tuntun to tun soju emin wa o, eledumare yio muwa ...

Read More »

Odu Ifa Ofun Meji/Orangun Meji Eepa Odu

 | | | |   |    |  | | | |  |   |   Ekaaro eyin eniyan mi, aojiire bi? Aku ise ana o, a si ku imura toni, oro wa yio dayo loni o ase. Odu ifa ...

Read More »