“Ọ̀rọ̀ ọkọ àti aya tàbí ohunkóhun tó bá kan ìfẹ́, ẹ má ṣe dá sí i, ẹ má ṣe gbìmọ̀, ẹ má sì ṣe ran wọn lọ́wọ́. Wọ́n ti lò mí láti yanju ọ̀rọ̀ wọn.” ![]()
![]()
Mercy Johnson, ẹni tí Regina Daniels ń pè ní Iya Isale(Godmother) rẹ̀, ti dá àwọn ènìyàn lójú lórí pẹ̀lú ọ̀rọ̀ yìí tí ó ń tàn káàkiri lórí social media.
Àwọn olólùfẹ́ Regina ti ń so ọ̀rọ̀ tí Mercy so yìí pọ̀ mọ́ àwọn ìròyìn àti àhesọ tó ń lọ káàkiri nípa Regina Daniels àti Ned Nwoko, pàápàá jù lọ lẹ́yìn àwọn ìròyìn pé àwọn méjèèjì lè ti tún pada sinu igbeyawo wọn.
Ṣé Mercy ń sọ̀rọ̀ láti inú ìrírí tirẹ̀ ni?
Tàbí ó kan ń fún gbogbo wa ní ìmọ̀ràn pé “ọ̀rọ̀ ọkọ àti aya, ẹ jẹ́ kí wọn yanjú rẹ̀ fúnra wọn”? ![]()
![]()
Ẹ̀yin náà, kí le rò pé òrò Mercy túmọ̀ sí gan-an? ![]()
Àṣà Oòduà Àṣà Oòduà
