Home / Àṣà Oòduà / Banky W àti Adesua Etomi ya àwòrán pèlú àwon òbí won níbi ìgbéyàwó alárédè won.

Banky W àti Adesua Etomi ya àwòrán pèlú àwon òbí won níbi ìgbéyàwó alárédè won.

Banky W àti Adesua Etomi ya àwòrán pèlú àwon òbí won níbi ìgbéyàwó alárédè won.
Tokotayà tuntun, Banky W àti Adesua Etomi pèlú ègbón Adesua Etomi okùnrin, ìyá rè àti àwon òbí oko ní apá òtún èyí ma tún dára Ooo.
Àwon òbí tí inú won n dùn náà kò yunra láti bá àwon omo won yà àwòrán.

About Awo

Leave a Reply

Your email address will not be published. Required fields are marked *

*

x

Check Also

Òfún kò rẹ́tẹ̀ be yín

Òfún kò rẹ́tẹ̀ be yín

A kì í wípé kí ọmọ olówó kó má se yín gan-an gan-anBó bá ṣe yín gan-an gan-an a o ni fètè ìwọ̀fà boA dífá fún Ọ̀rúnmìlà wọ́n ní kí baba kó fi ẹbọ araa rẹ̀ sílẹ̀Wọ́n ní Ẹbọ ayé gbogbo ni kí baba o seỌ̀rúnmìlà ní kí ọmọ Osó kó mà kú oBaba ní k’ọ́mọ Àjẹ́ kó yèNítorí wípé ẹbọ ayé gbogbo ni mo nseIre oo