Home / Àṣà Oòduà / Adanwo ni oro ile aye: Iku Abubakar Audu gba arojinle

Adanwo ni oro ile aye: Iku Abubakar Audu gba arojinle

Titi di akoko yii, enikeni ko le so pato ohun to sekupa oludije ipo gomina labe egbe oselu APC ni ipinle Kogi, Abubakar Audu. Se ise aye ni abi amuwa Olorun oba? Ohun ti ko ye enikan, kedere ni niwaju Olorun Oba. Olayemi Oniroyin, joojumo ni mo n kogbon aye. Gbogbo igba ni mo si n ran ara mi leti wi pe asan ni duniyan, omulemofo nigbogbo re pata je. Sugbon adura kan lo wu mi ti mo fe se fun gbogbo eyin ololufe Olayemi Oniroyin, ojo ti ire ayo yin ba wole de, imo esu ko ni ba ayo naa je. Odun n lo sopin, ibanuje, o kere, o tobi, ko ni wo ile wa. A ko ni rogun ekun, idaamu, wahala, ipayinkeke ko ni yale enikeni wa. Amin.

About oodua

Leave a Reply

Your email address will not be published. Required fields are marked *

*

x

Check Also

Gbọ́ ń táwọn èèkàn ìlú ṣọ lẹ́yìn Búrùjí Kashamu

Gbọ́ ń táwọn èèkàn ìlú ṣọ lẹ́yìn Búrùjí Kashamu Bí ọmọ èèyàn bá wá sílé ayé, ìgbàgbọ́ Yorùbá ní pérúfẹ́ ẹni bẹ́ẹ̀ wáyé wá nájà ni. Ènìyàn ò sáà lè tajà tán kò sùn sínú ọjà, àti pé n tí kóówá gbe wá sínú ayé fún títà kò papọ̀. Ìbà Ọ̀jẹ́túndé Asòlẹ̀kẹ̀ Olorì alágbàáà àná tó sílẹ̀ bora. Ó ní èèyàn tó wáyé wá ta góòlù kò papọ̀ mọ́ tẹni wáyé wá ta ẹ̀kọ.Ẹni o wá tẹ̀kọ ṣe é ṣe ...