Home / Àṣà Oòduà / Arábìnrin kan tí ó jé omo Liberia ni ó gé nkan omokùnrin òrékùnrin rè tí òrékùnrin rè sì pa á.

Arábìnrin kan tí ó jé omo Liberia ni ó gé nkan omokùnrin òrékùnrin rè tí òrékùnrin rè sì pa á.

Arábìnrin kan tí ó jé omo Liberia ni ó gé nkan omokùnrin òrékùnrin rè tí òrékùnrin rè sì pa á. Èyin òré wa, ejòwó e jé kí á máa fura nítorí a kò mo irú àwon obìnrin tí à n gbé nísinyí.
Arábìnrin yí ni ó gé nkan omokùnrin òrékùnrin rè tí òrékùnrin rè sì pa á fún èsan.

About Awo

Leave a Reply

Your email address will not be published. Required fields are marked *

*

x

Check Also

Aáyẹ tí ó de bá àṣà

Bí ó tilẹ̀ jẹ́ pé àṣà máa ń yí padà nípa aṣo wíwọ̀, ìgbéyàwó, àti bẹ́ẹ̀ bẹ́ẹ̀ lọ, lóde-òní, ètò ẹ̀kọ́ àti ìwà ọ̀làjú tó gbòde kan ti ṣe àkóbá fún àṣà ní àwọn ọ̀nà wọ̀nyí: (a) Ìwọsọ wa kò bójú mu mọ́. (b) Àṣà ìkíni wa kò ní ọ̀wọ̀ nínú mọ́. (d) Kí’yàwó ilé má mọ oúnjẹ ìbílẹ̀ ṣè mọ́. (e) A kò mọ ìtumọ̀ àrokò tí a ń kọ́ àwọn ọmọ wa mọ́. (ẹ) A kò fi èdè ...