Home / Àṣà Oòduà / Asake pade Lagidigba niluu London

Asake pade Lagidigba niluu London

Laipe yii ni Feyikemi Niyi-Olayinka, okan ninu awon sorosoro ori telifisan, dagbere irin-ajo re siluu London. Aworan re ni yii pelu okan lara awon osere tiata Nollywood, Sola Sobowale, niluu London. Lara awon fiimu olokiki ti Sola Sobowale se ni fiimu Lagidigba, Ilubirin (ilu awon obirin). Nigba ti OLEKU to je fiimu ti Feyikemi kopa gege bi Asake ko le pare ninu itan,

About oodua

Leave a Reply

Your email address will not be published. Required fields are marked *

*