Home / Àṣà Oòduà / Aworan Bukola Saraki nibi ayeye odun SilverBird

Aworan Bukola Saraki nibi ayeye odun SilverBird

Aare ile igbimo asofin agba, Bukola Saraki, wa lara awon alejo pataki ti won peju sibi ayeye odun marunlelogbon (35) ti won ti da ile ise SilverBird sile. Minisita fun eto iroyin, Oloye Lai Mohammed naa wa nibe lati soju Aare Buhari.

About oodua

Leave a Reply

Your email address will not be published. Required fields are marked *

*