Home / Àṣà Oòduà / Egbami, Erami kale omo oodua atata,

Egbami, Erami kale omo oodua atata,

eranmilowo
Egbon mi ati iyawore ngbe ni ilu Akure,emi ngbe ni ilu Abeokuta mo sese ri ise si ile itura(hotel) ti mo fi oruko bo lasiri,ojo aje (monday) ti okoja lo yii je ojo isinmin (leaf) mi lenu ise,sugbon nigbati mo de ibi ise pada loni yii,mo fe lo paro Aso ni inun yara wiwole ti mo wole,iyawo egbon mi ati ikan lara awon lecturer ti oko mi jade University ni moba ti won nfi enu ko enu ninu yara itura eru bami ohun ti mo gbe lowo jabo,mo pe egbon mi,egbon mi ni iyawo awon lo si Benin republic lati lo ra oja,edakun eslami loye kini kiun so fun egbon mi.

About oodua

Leave a Reply

Your email address will not be published. Required fields are marked *

*