Home / Àṣà Oòduà / Enu mi konipami enu re konipa e emi !!

Enu mi konipami enu re konipa e emi !!

sweet
Enu mi konipami enu re konipa e emi ati ore mi ajolo si odo baba kan ni adugbo wa nigba ti adebe. won ni baba ni alejo ni aba duro si ta sadede niaba gbo ohun arabirin kan tohun so pe gbogbo nkan ti ohun ba so fun oko ni ki oma se fun ohun ti ohun bani ki ofo aso kogbodo ko fun ohun kama fa oro gun nigbati obinrin yen majade lobadi iyawo egbon ore mi ni oremi ba gbalowo mun pe gbogbo ohun toso ninu ile ni ohun gbo ti ohun badele pe ohun mofun egbon oun kama ba opolo ile oloro lati bi osu kan bayi lara ore mi koti ya gbogbo ibi ti agbe oremi de ni wonti so funwa pe kise gbogbo ohun ti oju bari ni enu ma so. enu mi enu re koni se iku pawa lagbara olorun amin

About oodua

Leave a Reply

Your email address will not be published. Required fields are marked *

*