Home / Àṣà Oòduà / Ojulowo-ogidi iya je awon ole ti won mu ni Mowe

Ojulowo-ogidi iya je awon ole ti won mu ni Mowe

Ojo gbobo ni tole, ojo kan pere ni tolohun. Owo palanba awon igara olosa kan segi laaro ana ni agbegbe Olowotedo Mowe to wa ni masose Eko si Ibadan. Ikanra ni awon eniyan agbegbe naa fi na awon ole taa wi yii jalajala ko to di wi pe won fa won le agbofinro lowo.

About oodua

Leave a Reply

Your email address will not be published. Required fields are marked *

*

x

Check Also

Eto idibo gomina ipinle Kogi di fopomoyo

*Faleke n binu, ara ilu n sofo *Iwe ofin ruju mo awon amofin loju *Won tun ni kan fomo Audu je gomina apapandodo Leyin iku Abubakar Audu, oludije fun ipo gomina labe egbe oselu APC nipinle Kogi, eni to jade laye nikete ti ajo INEC kede wi pe eto idibo gomina to waye nipinle naa ku sibi kan, ni isele naa ti di ohun ti awon onwoye lagbo oselu ati eka imo ofin ti n forigbari nipa ona abayo si ...