Home / Àṣà Oòduà / Se N’Ibadan Tia Nile Oluyole?

Se N’Ibadan Tia Nile Oluyole?

Ibadan tia!

Se n’Ibadan tia?
Ibo lawa o mo lOluyole Ibadan?
MAPO d’AYẸYẸ
Gbogbo ODÍNJÓ tia ni,
ELEKURỌ, ALEKUSỌ,
Ibo gan-an lawa o mo n’Ibadan?
BẸRẸ titi to fi de ÒÓPÓ Yoosa,

Ibi to ku taa mo ni ke e wi,
Sebi Ibadan fe pupo.

ISALE AAFA, GBAREMU,MOSFALA,
Olayemi oba mo mọ Ibadan.

AGODI to fi d’ALAKIA ISEBỌ
Mo ti gba MỌKỌLA de YEMETU ri
Emi ti gba ỌJỌỌ de SASA pada bo.
ODO ỌNA yato s’ODO ỌNA ELEWE
Melo la fe ka n’Ibadan tiatia
Ka maa paro, Ibadan fe ju orileede ibo mii lo.

E tun le ka si nipa Ibadan nibi: www.olayemioniroyin.com/2015/08/ibadan-omo-ajorosun-ohun-to-ye-ke-e-mo.html?m=1

About oodua

Leave a Reply

Your email address will not be published. Required fields are marked *

*

x

Check Also

Àkó̩kó̩ Technical University Ibadan pèsè aso̩ ìbomú àrà ò̩tun fún ìpínlè̩ Oyo

Àkó̩kó̩ Technical University Ibadan pèsè aso̩ ìbomú àrà ò̩tun fún ìpínlè̩ OyoÌròyìn láti o̩wo̩ Yínká Àlàbí Akoko Technical University to fi ikale si ilu Ibadan se bebe ni irole ana. Won pese aso ibomu ara otun fun ijoba ipinle Oyo. Aso ibomu naa dara de bi wi pe o see fo, ti eniyan si maa tun rii lo. Oga ile-iwe naa, Alagba Abayomi Salami ati awon alase to ku ni won lo pese ohun iranwo naa fun gomina Seyi Makinde ...