Arábìnrin tí ó rewà tí ti jé kí elénu sónu níbi aso tí ó wò tí ó dùn tí ó sì tún se òwón (n se ni ó dàbí eni wípé ó wo bùbá àti ìró)ó wò lo sí ìbí ìgbéyàwó BankyW àti Adesua Etomi nse ni ó dàbí egbin.

Tagged with: Àṣà Yorùbá
A kì í wípé kí ọmọ olówó kó má se yín gan-an gan-anBó bá ṣe yín gan-an gan-an a o ni fètè ìwọ̀fà boA dífá fún Ọ̀rúnmìlà wọ́n ní kí baba kó fi ẹbọ araa rẹ̀ sílẹ̀Wọ́n ní Ẹbọ ayé gbogbo ni kí baba o seỌ̀rúnmìlà ní kí ọmọ Osó kó mà kú oBaba ní k’ọ́mọ Àjẹ́ kó yèNítorí wípé ẹbọ ayé gbogbo ni mo nseIre oo