omokùnrin gbajúgbajà olórin tí a mò sí D’banj tí orúko omo náà ń jé Daniel ni a gbó wípé Ó kú sí omi ní àná tí a mò sí ojó kerìnlélógún osù kerin odún yii.
Kí olúwa kí ó bá wa rò wón lókàn.

Tagged with: Àṣà Yorùbá